Stella Dimoko Korkus.com: E KU IGBADUN BLOG YI O

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, 12 October 2016

E KU IGBADUN BLOG YI O

Mo ki gbogbo omo oduduwa ni ibigbogbo agbaiye. Mo ki gbogbo ololufe sdk. 

Mo wa  ki Stella funrarare fun akitiyan re lori blog yi. Mo ki gbogbo Angeli oluranlowo to wa lori blog yi, Oluwa yoo ma a gbe owo yin soke (amin).

E je ki a gbe asa ati ede wa laruge lori blog yi gbogbo eyin omo Oduduwa ni Nigeria, Cuba, Brazil, America, London ati ni gbogbo agbaiye.


 Emi ni Abeke, isheri omo oloko, omo olu nla, omo tana o to je su aya won ni ilare, Ile Ife.


*Abeke Ese pupo.mo busy gan tabi ma ba eyan mi chat ni...kikikikikikiki

189 comments:

white Berry said...

Noted, please I need a translator on this.

Loveme Jeje said...

Ekaro ooo omo mi. Se owa kpa. Ekushe ooo

Blackberry said...

Mo fe dobo mabinu, lol.

Pipi Lee said...

Kikikikikikikikikikikiki, the struggle to stay relevant is real...hehehehehehehehehe

Eku gbadu o, ma yoruba brethren.

Niklaus said...

Emi na ki e Abeke. Olorun ma ke e. Omo calabar ni mi o sugbon mo gbo ede yoruba daada.*mo fe wa laye ti ti ayeraye*

Leo Queen said...

inn okun o sisita sitella,se alaa ni?

Giselle Lawrence said...

Oni a dara o Stella.

Anonymous said...

Abeke was gbayi!! Omo oduduwa to splufic..

lastborn said...

Kilode ti e fi ami faweli si yoruba ti e n ko.

Niklaus said...

Ki'n to gbagbe. Shey Blog o ni nkan ti'n won pe ni ede yoruba ni? Awon omo ibo ma wa sibe wa shey wahala sugbon KOLE WERK.

youngman said...

Stella has got ingenuity and this makes the blog unputdownable.

I don't know kpikim in Yoruba. I slayed my Igbo joyfully the other day, so Yoruba speakers carry go

Debbie me said...

Ema binu o, odabo. Kikiki.

Becky Divine said...

Phewww

Fierce of SDK blog said...

Abeke,oshe pupo,olorun awaa pelu Iwo ati awon ara ile re gbogbo. Abileko 'Sitela',oku use takun takun,emi n gbadun gbogbo a won nkan ti mo n rii Lori bulogi re yii o. *wipes sweat*

CHI EXOTIC CHI EXOTIC said...

Eyin temi kilon sele?
Se gbogbo e nlo?

Mo fe sare de salon
Ma ri yin to ba ya.

Bolty said...

Mofi asiko yi dupe lowo Abeke fun akitiyan ati gbe ede wa laruge. Motun fi asiko yi dupe lowo SDK omo araye onibayo e je ooo. Amin.

ukwu dimond said...

just passing .......

Justina Michael said...

Hmmm

Anonymous said...

Ni Ohun kiss Daniel " Stella ngbo o dat am sorry as I read your yoruba Erin ni mo Rin*

Anonymous said...

Na so e be now? Make me self go compose isoko blog post come send to stella. Isoko wadooo! Isoko wadooo! Wa dhe?

Vivian Ezeadum said...

who wrote this

I thought Stella don't know how to speak yoruba

Lateesha Pasteries Ajjah Lagos - 07032392414 said...

Dint understand a thing.
Please I need a good translator.

Vivian Ezeadum said...

I wish I can understand yoruba eh

White Diamond said...

Omo ale jati jati. Ole. Oko mi. Iyawo mi. Edada! Omo Yoruba. Ko possible. Ekaro. Ekabo. Ekuse. Emabinu. Ermm...

#WhiteDiamondOut

Pure Nigerian said...

Ikpi kene itang k'iko ukang nyin, ekpa e do ikod?

I can read and understand your language Abeke but can you read and understand mine? See, why you should be considerate of other BVs.

Emi na ki e pada, Abeke. Angeli wa e seun oh, amin fun adura ti Abeke gba fun yi

Ideato/ilaje blood said...

Must u guys copy? Be unique for one.

Lemme call my ilaje mother. Brb

Blog Member Ibukunoluwa said...

Stella ur Yoruba no be am😂😂😂
Bawo nii eyin ara ile...
Aku dede Iwo yiii
Emi ni Omidan Ayinke Ade😘

Mosi Jubelo said...

I tried, I could actually read it.

De Unbreakable said...

Lol, the only thing i could read and comprehend is "ĺori blog yì"

zovik global said...

Ahia ndi uka abiala.

Awele said...
This comment has been removed by a blog administrator.
Amysweet said...

Eka sun eyin eyan mi lori blog yi. Se Alafia le wa? I hope say I try btw am Igbo

Awele said...

Ko ara eh kuro nibi,yanmirin.

Blog Member Ibukunoluwa said...

It is Ekasan
You got the rest right

Mrs shantelle said...

This Yoruba Bvs go sleep here today. Lool......let the comments start rolling in.....

bee said...

o kare stella

Anonymous said...

Ekaa'san eyin eyan mi ni'bi gbogbo te tin ka bulogi yi kaakiri agbayeOwo meji fun Iya afin Korkus fun eto yi, gbosa ogunlogan fun gbogbo angeli at'orishe ori bulogi yiAshejere ama je ti gbogbo wa, Olorun a ma da aabo re bo wa, Amin.

Emi ololufeyin naa ni,
SHARONNA

Anonymous said...

*wa

Amysweet said...

Lol.. Thanks

Anonymous said...

Stello olodo .why you no write (blog) for yoruba...se o wapa ,stella iyawo cockus.

LusciousM said...

Haha.. Anti mi Leo, shey omo okun niyin ni?

SONIA SPENCE ✌✌✌ said...

Ekaro oo awon beefees


Eshe gon Stella

Mhzzbee int'l said...

Mo ko gbo gbo ile ooo, inn Ora, inn Okun ... Ede ekiti ni mo so yen ooo. Inn ara ekiti, ati inn toku se dada lewa ooo.

Omo ekiti to gbayi 😄😃👍

Apples ( SDKBlog Shrink) said...

Clown!!!

Apples ( SDKBlog Shrink) said...

Hian! Go to the Igbo post!

Sweetheart said...

I'm yoruba..couldn't read the last part. Abeke! Chop knuckle.

Adetutu Babatunde-Edward said...

Abeke gbogbo ile kin e, ose to gbe Ede wa laruge. Ede to lewa ju lo #tongueout#. Ede to lasa ati ewa. Eyin omo odua eku reccession yi oh, Olorun a ko wa yo

Adetutu Babatunde-Edward said...

Abeke gbogbo ile kin e, ose to gbe Ede wa laruge. Ede to lewa ju lo #tongueout#. Ede to lasa ati ewa. Eyin omo odua eku reccession yi oh, Olorun a ko wa yo

Apples ( SDKBlog Shrink) said...

Ema binu, Yoruba mi baad ghan, Omo Yoruba ni mi o! Hope I've not destroyed my language? Chai! Lmao!

SWAG LAFRESH said...

Hahahahahahha 😂😂😂😂😂😂

SWAG LAFRESH said...

Hahahahahahha o dabo

SWAG LAFRESH said...

There's nothing like copy here. Stella has done this in the past. Wait for hausa version.

Mhzzbee int'l said...

Bawo ni gbo gbo Omo kaaro oji re bi.se ala ni se?omo ekiti nimi re ooo, inn Ora, inn Okun kete Omo ekiti Lori blog yi ooo.😄😃😃😃
Stella ku ise takuntakun,olorun a San e no esan ire ooo, awon Omo e aye ooo(Amin).

Anonymous said...

O mo ju obo lo ni? Onise kuse, onido ku do,LOL

Ikuenogbon Boladale said...

Mo tun gbadun eleyi o, o dara ki a gbe awon asa wa laruge. Ko si ede ti o dara tabi ti o lewa ju ede miran lo. Yoruba ni mi, inu mi si dun gan lati je omo ooduwa.

Abeke o kare lae. Apeke loruko oriki temi ire o.

Kim Kardashian Aka portable queen of sdk blog said...

Just passing..... Iranu

Kim Kardashian Aka portable queen of sdk blog said...

Ewa joko...

Omolabake bukky said...

Eleyi gidi gan ooo....... Ori gbogbo wa m be

Kim Kardashian Aka portable queen of sdk blog said...

Ewa joko...

OD said...

Emi o kin se omo Yoruba o. sugbon mo gbo yoruba ju elede yoruba lo. Stella oku ise takun takun, owo e ama ro ke o ni agbara olorun, olorun a si ma wa pelu e ati awon omo e and oko o, ni oruko Jesu kristi. Amin.

Ozeiza omo Ebira lon kin yin pe oda bo.

Anonymous said...

Abeke, Ose omo iya mi, wa se opolopo ori re,Gbogbo omo odua, mo ki yin. Emi ni omo na biggy.paul@yahoo.com

peace maker said...

Where are the omo oduduwas or afonjas?
They should get in here

Anonymous said...

O ba iya gbogbo éyin ajékuta maa momi,e sha amin kingbo

Chummy cho cho said...

Ebingba mi gan... Taloni guguru ati ekpa?😄😄

Empressitta said...

Same ere dear, they got u today lol after we flexed our igbo for them.

PinKy berRy said...

Whity what did u just typed? Hohohohohi

PinKy berRy said...

EKu se omo gbogbo aiye o

Muah said...

Stella kin she abileko o, iyaafin ni. Ile oko lo wa fa

Olabisi Evelyn said...

Ekasan gbogbo Ile, se Dada la wa

Anonymous said...

Shut up bitch,this isn't the 1st time SDK will be doing this.Im sure Hausas are having theirs tommorow.Olorikori omo.

Malumi Dont Beat Mi said...

ste ste o ma try gan
mo ri pe o shey biri biri bi obirin
olorun ma wa pelu E oh
gbo gbo nko ti o ba fe ki odun yii ko to pari
Olurun ma fun e sey...
gbogbo family sdk awon ti wan fe oku abi iywawo olurun a run ageli fun yii oh..
loruko jesu christi olu wa wa
eei aleluya meji
o go
ogo
ogo

EESAH (Christ Lover) said...

Mon ki gbo gbo ile

Aa fe ri nyammiri kan nibi o. E ma wa ba ede wa je o LMAO

Anonymous said...

Stellastico Stella, o se gan. Ku ise opolo O. Oke oke lowo re yio maa lo.
Wa ri batise, wa ri ona gbegba. Oni bawon Ku iku owowo. Amin lase Edua
AMBER

Martins Aboy said...

Ki le leyi so??

Ko easy rara ooo..kikikikiki

@MARTINS ABOY

Anonymous said...

Hmmm, Iya Afin Sitela eseun fun aye ranpe yi lati so ede Abinibi wa, ki okuwa ki o bukun fun yin ooo . Ara birin Abeke Ku ise na. I Dabooooo..

nnuku sells Sexy pant-like boxers. Order now said...

Ofe dobo? I hope u understand wetin u write so?


**Order your boxers, Singlets, socks, @ affordable rates. We deliver **

I am the queen and the boss of this blog said...

This Awele is very stupid!...

nnuku sells Sexy pant-like boxers. Order now said...

Ori yi ti yi sir. Nobody asked you to insult any tribe or shade any tribe, na so una dey do dey cause katakata up and down. Agbaya Jati Jati. Airhead.**Order your boxers, Singlets, socks, @ affordable rates. We deliver **

SHAKITI BABY said...

Mo ki gbogbo ile oooo.
a o ni ku ni kekere.
Odun yi o ni di wa maru lo oooo.
arabirin stella,ku ise ribiribi ti o n se ninu ile aye.
Olorun a sa esan fun e.
Awon Omo e ma ri alaanu.
mo ki gbogbo eyin elegbe mi pelu.

Iya afin linda Eze.
Iyawo Ogagu.ati beebelo.

SHAKITI BABY said...

O gbiyanju

SHAKITI BABY said...

Awada e po.
tesi oju e.

kaycee Blinqs said...

Ano M na eche this post kemgbe Ndi Igbo mere nke ha... Chaii. Ofe mmanu na copy copy. Unu bu ya na ishi. Ahubem!. Ekelem Unu ooh nu!

Marcel Omoleye said...

Se Ekiti loore ni abi Ijesha?

SHAKITI BABY said...

Obo aja abi ti malu?

Olaide Davies said...

Mo like blog yi bajebaje, Abeke, yio dara fun o.Stella o seun o.

Just Glamour said...

Yes oooo,you did well,Eka Joy we need your attention here,come and do the needful.

priceless pearl said...

Ekiti niyen ke,a mora wa taaba ri ara wa#kikikiki

Muah said...

You are right and am wrong. Just checked up

Awele said...

Nnuku pele oh,oja eeh ko ta leti awon bvs mo.Onibara,lo waye si egbe raluwe ni Agege ,awon egbe eeh wa ni be.

Awele said...

Queen:iya were onisekuse,shei mo ta si eh ni?Lo do oko awon omo keekeekee to mo do.

Fluffy cake by Big Mamma Lagos 07056157039 said...

Abeke, oo osheeeeeee.

Anonymous said...

Bia, who is struggling to stay relevant. Tribalistic, educated illiterate.

Anonymous said...

Stella ti o gbe Ni ilu eko..bi ko ti e le so, o ma gbo ede yoruba diedie.

Anonymous said...

Se Yoruba Ni e white diamond

abisoye ologbenla said...

Lol weirdos

White Diamond said...

Lmao! I am 'sparking' Yoruba o.

#WhiteDiamondOut

Anonymous said...

Everybody is trying to be relevant by abusing tribes on stella's blog o ga o. Bo ya won de un fun yin Ni ebun fun eke ebu Ni.

Eka Joy said...

Mi o fe ran yi lowo loni, ki won to wa pe mi ni sabinus. Mi o le wa pa ra mi

Anonymous said...

Seriously maid of this blog, that is how you always sound too that makes two of you...but I believe awele is learning where your own stupidity start from.

Eka Joy said...

Did u have to be tribalistic? Oloshi oloriburuku, ikeji eku

Anonymous said...

Omoluwabi patewo fun ara e.

Anonymous said...

Kikikikikikiki

Anonymous said...

Omo a fi ipa ji iya ati baba re Lori ibusun a copy copy yin O.

Anonymous said...

Eku dede iwoyi o. Moki gbogbo yin lokunrin lobirin, lomode ati lagba. Inu mi dun si blogiyi mo si dupe lowo arabirin Stella aya Korkusu ni germani. Eku ise naa olorun atunbo maa ran yin lowo, osi ni shise , oju ooni tio loruko Jesu kristi . Mo tun fi asiko yi dupe lowo gbogbo angeli funi funi ori blogiyio lorun aamaa gbe owo yin soke eni sunku o. Gbogbo awon eleya meya ori blogiyi ni mo kio eje ki ife lorun ko joba laa rin wa, emase jeki ede ko ya wa, ki aye sebi Omo iya awusa. Olorun yi o duro ti gbo gbo wa o aaoni ba odun yi loo. Lati ilu morika ni motin ki yi o. Odaabo

Pure Nigerian said...

That's not Igbo language

Starjoy said...

Ekasan awon inyomi

ilovemylife said...

Mo ki gbogbo yin o!

Awele said...

Oloriibu lo ko si konga.I can bet your smelling ass is new here.Wait for the Hausa version tommorow.

nnuku sells Sexy pant-like boxers. Order now said...

I shouldn't have dignify you with a response. It obvious you have got serious ringworm in your brain. Alainironu

Anonymous said...

Gbayi stella, abeke nle oo omo Oodua tooto.

Olori footwear said...

Pipi Lee why?

Anonymous said...

Ikeji eku yeeeeeee, Eka joy ti finish maid of this blog. Kikikiki

Bee10 said...

Blackberry please leave me alone.😃

Anonymous said...

The way the igbos sleep on their own too I guess

Anonymous said...

Omo a fi ipa ji baba ati iya e ki ni won un copy lara yin o

SWAG LAFRESH said...

@shakiti baby no kill me with laugh 😂😂😂 obo malu

SWAG LAFRESH said...

Stella delete please

Pipi Lee said...

Lmaoooo...uneducated literate, I actually struggled to stay relevant by writing something no matter how small in your language.
#ByeAnonymousTribalRat

Anonymous said...

Kikikiki @recession
Amin o

MrsBee

D'Royalty (STELLA'S BLOG BFF) said...

Beeni oo
Awa Omo oduduwa ni a dara julo ni Orile ede yi
Ema se tele awon omo yanmiri wonyi ti won nife is ijogbon. Awa omo oduduwa lo ri bulogu yi nife si alafia. Emi je okan ninu won.
Stella, dakun se posti lori ede ilu mi, ede awon ti won ma n je eniyan, ede ore re yen to rewa daada....
Ikwakwakwakwakwakwakwakwakwakwakwa

My ofe mmanu language is on fleek, you need to hear me speak it..... Wetin dem dey call people wey sabi speak plenty language? I dey come make I go google am.

Anonymous said...

O Kara lai, okan shosho ni gbogbo wa

MrsBee

Anonymous said...

Ebi npa mi lo fe so, o gbiyanju👏🏽

MrsBee

Anonymous said...

Ogbon gbogbo wa ko ni baje oooo#okannioriledeNigeria

MrsBee

Andromeda O said...

O sha mo!

Andromeda O said...

Ibeere.
Lol!
Mo n sere ni o

Andromeda O said...

Abi...
Niklaus, omo 'yibo' la n pe.

Andromeda O said...

Hahahahaha.
Mo gbadun post yi
Amo, emi kin se omo Yoruba.

Andromeda O said...

Amin l'orukø Jesu.
Ośe

Andromeda O said...

Tootø

Andromeda O said...

Gbenu oshi soun, omo yibo!
E ri ori e bi fila

Andromeda O said...

Mo ki yin, eyintemi!
Blog yii, ko gbø dø baję ooo
Mo ni ife to gbona felifeli fun efribody.

Andromeda O said...

Lmao

Lara Peperenpe said...

Aja lo ma a je enu iwo omo kpikpi Lii yi. Ta l'egbe iya la ya e nibi? Pare bi iso...

Lara Peperenpe said...

Kare jare!

One trillion said...

End time Oduduwa

Lara Peperenpe said...

Aala funfun gbo ooo.
Omo Ekiti ni me ha.
Okun awe...
Maa ju'yan re lo luka luka

Lara Peperenpe said...

Ose, padi mi Chi to wa exotic.
Mo n feel e gan
Je knuckle

Priceless Jewel said...

Omidan Stella, oku ise ribiribi ti o n se ni ori blogi yi, Oluwa a ma so agbara e di otun. Oku itoju wa ati awon alai ni ti o n ran lowo, oju oni ti enikan kan wa oh, asi dara fun gbogbo
wa o, amin! Between I'm Edo...

...Jesus is my worth!

Lara Peperenpe said...

Hahahaha
Awele mo n gbadun e gan!
Bwahahahahaha.
Ki won gbo won ni 'gbokugbo abi?
Ki won tun te e s'oju e fun wan.
Girl yi funny sha.
Kakakakaka

Lara Peperenpe said...

Sharonna baby,
Gbogbo Ile nki e o

Lara Peperenpe said...

Omo Ekiti ni me ha.
Ke happen?
Se ala ni?
Uyan a yun lerun re.

Lara Peperenpe said...

Shakiti omo mi
Gbogbo ara ni mo fi nki e

Anonymous said...

Ewe soo dede ewen omo alaare...

Lara Peperenpe said...

Eka joy won't see this and scold him.

Omo osan to nko ponpo ba iya e @kaycee
Bi won se ma nfori k'epe niyen.
Olofo!

Pipi Lee said...

Aja lo ma a je enu iwo omo kpikpi Lii yi. Ta l'egbe iya la ya e nibi? Pare bi iso... @Lara Pererenpe

ademola ifesanmi said...

I'm not omo Oduduwa. I'm an Ilaje guy. My forefathers were/are the owners of the Great Ife city. We are the progenitor of the Yoruba race, not Oduduwa

Anu Funke said...

Lara alabajo ti mo maa'n gbadun e, asé omo Ekiti ni é.. 👍👍

Iñ orà oo kete ulé... Sé ala loi a?
Kete rà lao keré oko dele o lasé loí Eledumaré.

Anu Funke said...

Oní a sañ a ooo...

Anu Funke said...

Kare lua mí... Omo Ekiti ni me à
Lara okun ooo.

Anu Funke said...

Mi o tí ri Sunshine nibi yi o, ibo lowa? Tori momó wipé omo yóóba toja fafa ni.

Ekulé gbogbo ara ile.

Eyin omo Ekiti mofi gbogbo ara kii yin oo, iñ pele oo

Anonymous said...

Fuck shitt! Pls translate "Nigeria" in your language.
Yoruba:
Ibo:
Hausa
Edo
Isoko
Urhobo
Calabar
Esah
Itsekiri
Akoko Edo.
In Patt Ogar's voice leave your name, account number, bank name under your answer, I will deposit the equivalent of $50.00 into your account. I'm doing this for my birthday coming next month.
##Sagittarius.

Eka Joy said...

Lara, eleyii ko bu Ilu yin bi awele. Abi shey copy copy tun ni ebu nla ni?


OK, on a more serious note, awele went ahead to really insult the igbos, how can u compare it to ordinary copy copy.

Or, is it cos he said ndi ofe mmanu, read up and you'd see that we were called awon aje okuta mamomi and I didn't complain about that.

DAMI said...

Awele is only putting his or her humor to use
after all majority of you say worst

Anu Funke said...

ere tete ni mosa debe, uya lenu nije fun mi pe e siun konkon ko je 'pajawiri libé. Ti ede yooba to koja dun ju yee lo #inekitidialect

i rushed to this place (thread), was surprise to find out that there is no emergency.D last post abt yoruba was more interesting than dis

ademola ifesanmi said...

Ayemafuge Ilaje! Awa yeeee.. Ideato u correct. Aha un re!

Anonymous said...


Please translate smelly pussy in Yoruba and Ibo language.

Alabi Ganiyat said...

Akiyin gbogbo omo yoruba SDK.. Dada lamo bara wa se o... Amin.

Anonymous said...

Pipiliyi onoranu, nsoro aja njo. Omo ale jatijati!

Anonymous said...

Aala ni o.
Iyan a yun lenu re awe!

Anonymous said...

Bulogi ni a mo si ni silebu Yoruba.

Anonymous said...

Eka joy karin kapo, yiye lo n'yeni. O le mumi a, ko jata a lofe o. Ajemonu lawon arami lokunrin ma fi o se gbeyin.

Anonymous said...

Obirin to wa ninu ile oko ni yoruba npe ni Abileko. Abileko ni Sisi Stella o.

Anonymous said...

Ori e wa nbe Jo. Igbe e onile, o mama to ni.

Awele said...

Eka sorry dear,I know you're frustrated.
Nnuku onibara,you now have mouth to talk back at people abi,ugly duckling.Like I said before get a spot at Agege railway,that's where you're colleagues are.

Awele said...

*your

Anonymous said...

Naija Ponbele, a ki binu ori ka fi fila de furo o. Se ilu abinibi tire ni Abeke ngbe bi? Jowo dari ikanra re sodo stella, ko le gbe ipele iru eleyi naa jade ni ede ilu re.

Tush baby said...

Copycats bc someone posted in igbo.

Awele said...

Eka bitter soul keep around this post like a headless chicken .

Anonymous said...

Won ma peyin, ko ti kan yin!

Anonymous said...

Soon you go begin form old bvs from jalabiya days with no memory of stella doing this post in nigerian main languages turn by turn.

Anonymous said...

Still on uniqueness and relevance. Pls remove ilaje from ur ID name, you claim to have their blood but you never hesitate to make hateful comment about them. Omo ale jatijati, akotileta.

Anonymous said...

Ideato author of confusion. O komi eshin da sile eran, komi eran da sile eshin. Abaniworan baarida, o suna sigi, sungi sina. Tori iru awa omo oodua ko o, tori awon ebi e ni. Omo irankiran!

Anonymous said...

And u're finding it difficult to stay away from the party. Omo irankiran!

Anonymous said...

Time keeper!

Anonymous said...

May ur life be saved from i must comment spirit. Na by force to comment?

Anonymous said...

Relevant on an unknown blog you mean Kai lack of sense

Senior People said...

Is that Annang?
Ayaya

Miss Tet said...

Mo ki gbogbo omo kaaro o'jire to wa ni bulogu yi, se alafia ni awa? Anu ati ojurere olorun o ni fi wa sile o. Abo re o ma wa pelu wa lai ati titi lai Amin🙏💋

Anonymous said...

Hahahhqhahh,in okun awe,emi eyin loju Olodumare ni moun ki yin oo,omo owor madeh

Anonymous said...

Éyin eyan mi,ni ise ni ke ló wo bulogu akant anty to wa lo ke yi pelu ti anty to fun ni owo lé ni.Opolopo akant ni enikan shosho ni lori bulogu yi.Áafe ju mewa lo

Anu Funke said...

Karé lu a mí.. Anon 18.51

Awele said...

*running

Fab_divas online store for designer bags, footwares and clothings said...

Ale o..'Egin ma e ki won oo
Se mo ba won i ye!!...
Inumo dun lati yi beiyi oo
kikikikikikik..Who no understand!!

nnuku sells Sexy pant-like boxers. Order now said...

See this tse-tse fly. Hian. shey o ni opolo ni? Tabi o ni Arun opolo? Which one is wrong with you. U must b very stupid, talk back, I know u bfor, abi I dey fear anybody for this blog bfor? Mtcheeew. Ori yin kope rara ma. Shey u wanna b stupid, I will b your anti-stupid on this blog.

Pipi Lee said...

Anon 18:47&20:02... onoranu, nsoro aja njo. Omo ale jatijati!

Oluwaseun Kutı said...

Eku gbo gbo lori blog yi o. Oluwa a fun wa ni itura nipati igba Buhari yi o. Ase.
SDK, eku ise takun takun lori blog yi. Mo si ki gbogbo omo Yoruba, eyin ara wa ni orile ede ati awon ti nbe ni oke okun.

Egba la wa. Ba a wa

BluntIjebuChic'*GiFTED'* said...

Ara ule mo waja..e okun OK kete omo ekiti

BluntIjebuChic'*GiFTED'* said...

O dabi pe ati ohun rinwa ni babe yen

Snowflakes said...

Lara peperempe,mo wo'she e ju... Ori e pe bi ori alajo shomolu to ta moto to fi ra keke
Omo Ado oraaa ni mehia,awa lomo amu'kara sabe ewu je....

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...