Stella Dimoko Korkus.com: Aseju Baba Asete.......

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, 25 October 2017

Aseju Baba Asete.......

Ejoor,se egbo yoruba ni?

Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari iwé mẹ́fà, gẹ́gẹ́ bi ọ̀dọ́, ó gbéra lọ si ilú Èkó nibiti ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Ẹlẹ́ja.


Ó nṣe dáradára ni ibi iṣẹ́ ki ó tó gbọ́ ìròyìn ikú bàbá rẹ. Ìgbéraga pinu lati padà si ilú rẹ lati gba ogún ti ó tọ́ si lára oko kòkó rẹpẹtẹ ti bàbá rẹ fi silẹ̀. Ohun fúnra rẹ ra oko kún oko bàbá rẹ ti wọn pín fun. Ó di ẹni ti ó ri ṣe ju àwọn ọmọ bàbá rẹ yoku. Eyi jẹ ki gbogbo àwọn ọbàkan rẹ gbójú le fún ìrànlọ́wọ́.


Ni igbà ti ó yá, o ni ilé àti ọlà ju gbogbo àwọn yoku ni abúlé ṣùgbọ́n kò to, ó bẹ̀rẹ̀ si ra oko si titi dé oko àwọn ọmọ bàbá rẹ yoku. Eyi jẹ́ ki ó sọ àwọn ọmọ bàbá rẹ yoku di alágbàṣe ni oko ti wọn jogún. Inú àwọn ọmọ bàbá rẹ wọnyi kò dùn si wi pé wọn ti di atọrọjẹ àti alágbàṣe fún àbúrò wọn ninú ilé ara wọn.


Yorùbá ni “Àṣejù Baba Àṣetẹ́”. Ìgbéraga bẹ̀rẹ̀ si ṣe àṣejù, kò dúró lati má a fi ọrọ̀ rẹ yangà si gbogbo ará ilú pàtàki si àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ, ó jọ ara rẹ lójú, ó si nsọ ọ̀rọ̀ lai ronú tàbi gba ikilọ̀ àwọn àgbà ti wọn mọ ìbẹ̀rẹ̀ rẹ. Kò mọ̀ wi pé ohun ngbẹ́ ikòtò ìṣubú fún ara rẹ́. Ni ọjọ́ kan, ó pe ọ̀kan ninú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ ti ó sọ di alágbàṣe ninú oko rẹ tẹ́lẹ̀ ó si bu, ó pe e ni aláìní dé ojú rẹ. Ẹ̀gbọ́n ké pẹ̀lú omijé lójú pé “Bi ó bá jẹ ìwọ ni Ọlọrun, ma ṣe iwà burúkú yi lọ, ṣùgbọ́n bi ó bá jẹ́ enia bi ti òhun, wà á ká ohun ti o gbin yi”.


Alágbàṣe ni oko Kòkó ti wọn jogún – Working as Labourers in their inheritted Cocoa farm.


Ni àárọ̀ ọjọ́ kan, Ìgbéraga ji ṣùgbọ́n kò lè di de nitori ó ti yarọ. Wọ́n gbe kiri titi fún itọ́jú ṣùgbọ́n asán ló já si. Ìṣòro yi jẹ ki ó ta gbogbo ohun ini rẹ ti ó fi nyangàn titi o fi di atọrọjẹ.


Ẹ̀kọ́ ìtàn yi ni pe àṣejù ohunkóhun kò dára pàtàki ki enia gbójúlé ọrọ̀ ilé ayé bi ẹni pé àwọn ti ó kù kò mọ̀ ọ́ ṣe, nitori Yorùbá sọ wi pé “kìtà kìtà kò mọ́là, Ká ṣiṣẹ́ bi ẹrú kò da nkan, Ọlọrun ló ngbé ni ga”.


Bv Olori Orente

131 comments:

Miss Ess said...

Ku u lakayee bv orente

BLOGLORD (MVBM) said...

E ka ro
Eku jor meta?
So wa ok?
Ma pada lola so gbo?
Later

😁

Olori Orente said...

Oya gbogbo omo kaaro ojire ebo sibi ooo
Eja ka fomijomi toro oro

MelaninQueen said...

O seun jare Bv Orente,igberaga lo ma saju ibarun. Itan ti o mu ogbon wa ni ooo.

Eyin temi bawo ni ooo???

Anonymous said...

Meaning please

Anonymous said...

Yes oo.. I heat Yoruba


Aah aah aah... Ma mA Ma MA fueh ni igbati

Aah aah aah aah.... Shay owa alright


Aah aah aah aah... Wa DOBO


Abi, no be so Dem dey open mouth talk? Aah aah aah aah
@ANONYMOUS ORUBEBE

Anonymous said...

Hmmm...oro baba oro. Ese Olukotan, igberaga ni n siwaju iparun. Eje ka saiye jeje ka ma ba parun lojiji.

Iya Oshoronga of Blogosphere AKA Mrs Always RIGHT said...

Igberaga l'on shiwaju iparun. Good story. Never use your blessings to torment other people because the table can turn at any time. Olori orente eshe pupo o.

Debi said...

Hmmmmm

Yori Yori Princess Loveme Jeje said...

Yoruba ti de oooo. ekaro gbogbo ni ile ooo.

Mombo

SANDY YO said...

Ehen good! Atleast, It will make Iya to leave our Igbo post in peace.
*strolls out*

Sharon Aminu said...

Abeg my brain is paining me😁😂😂

Morenipamper said...

Olorun a gbe gbogbo WA GA. Amin

Joblesshousewife said...

Orente, Well done! Ah! Alaseju ni Igberaga o!

GODMADECHIC said...

E ku agba Olori Orente. Eko gigidi ni eyi je fun gbogbo odo ode oni. Bi isu eni ba n ta amaa fowo booje ni. Shebi eni lari, shebi Eledua lomo la. Agba yin adale olori laafin.

Awon omoge ati broda "instagram" e gbe joko ke wa kogbon.

Oro ti jade, ashe ti tele lati enu Olori Orente!

Ed said...

Mi e gbo yourba. ..die die.... Ka aro o😙😙

The General's Wife said...

Mi omo o-Me I don't know o!

Tani- who is that?

Oloshoo-ashi

Oko-A village in my state.

Obo ni e- You are a monkey!😂

Bawo ni o my Yoruba friends!😃

Anonymous said...

Lesson well learnt. Thank you BV orente.

OLORI said...

As I be Yoruba girl sef I no fit read everything.....eku owuro ooo.

Shey daadaa le wa?

Olori orente you forgot to put copied cos I'm sure u no fit put those signs

Cute hajia Omo Mummy said...

Omo Yoruba ni emi sugbon mio o mo yoruba ka dada... Eshe gan Olori..

Chike TEFLON said...

Ki lo so?

Mi o gbo...

Kini gbo gbo eleyi? 😂😂😂😂

Olori Orente eshe gan 🙌🙌🙌

Omo Yoruba ewa wale ooo

Chike TEFLON said...

Oda aro
Mu bo🏃🏃🏃

Love.Eating.Pussy said...

Igberaga ma n kò eyan si wahala ni
BV olori orente this is a very good write up.

LEP😛

Chike TEFLON said...

Lol
Kilo de Sharon Aminu my future ex Bae?

Saved said...

You heat yoruba? Oniranu oshi, u for cold yoruba.wo bo se ri bi igi ishana

Chike TEFLON said...

Lol
Eshe gan.

Iya ewa ooo

Mbo lo lo?

Ewa se😂😂😂

The General's Wife said...

Ehen I forgot, Olori Oshe kpukpo!👍

Chike TEFLON said...

Nekwanu umunnem na aRAPuzi Yoruba.

TGW
Ijele dike
I did not see you yesterday during Igbo post. Mbo lo lo?

Chike TEFLON said...

BLOGLORD the real MVBM.

Ba wo ni?
Shey da da ni?

Chike TEFLON said...

Eshe gan Olori Orente 🙌🙌

Chike TEFLON said...

Ed na only this one you sabi speak?

So ro joor!
Ah!!! Ki ni gbo gbo eleyi 😂😂😂

Anonymous said...

O seun pupo alejo buloogu Orente (blog visitor orente)
igberaga lo n siwaju iparun, agidi okan lo n siwaju isubu.

Onirele lo le jogun aye, bi isu ba ti e ta, sebi o ye ka dowo bo je ni.

Eleduwa paapaa korira agberaga sugbon o fi owo fun awon onirele.

O seun pupo leekansi Arabinrin mi, tubo maa gbe Asa Yoruba ga nibikibi.

Eyin ara mi lori buloogu alayo yi, Ire oooo

Alejo Buloogu OmoBee. (BV OmoBee)

sexy Daddy said...

Iya, hope you will now rest and enjoy your own local language!

gbemmy said...

Igberaga lon siwaju Iparun- Pride goes before a fall
Aseju ohun gbogbo ko da- too much everything is bad,do everything in moderation.
Agboju logun fira re fun iyaje- the one who relies on family wealth,only exposes his or herself to suffering.
Olowo kan otosi mefa,otosi ni gbogbo won- A rich man in the midst of six poor men,translate to seven poor men,teach people how to make wealth rather than giving them piecemeal.

Lessons of this write up.

Aunty Stella ese gan ni o

I will be waiting for another write up in Igbo,will be ready to interpret for you, ngwanu...

sexy Daddy said...

Iloron ikotun Yuri gbede fii ko Ryan igberaga.Bv Orente.Bawo in..Lol

Kendrick's mum said...

Eka'aro o

Ekujo'meta

She'wa'ok?

BV Olori Eshe gan!!

Aréwa said...

Igberaga ni o siwaju iparun. Mase se igberaga si enikeni ki o ba le gbe ile aye pe

Olori Orente said...

Eyan mi eseun

stella dimokokorkus said...

awon eyon mi bawo ni nkan be?

mo fe lo yagbe se...
mon bo oh.... *releases fart*

Olori Orente said...

Bloglord
Iya toh jaiye juu
Emape ke to de oooo

Olori Orente said...

Awa pa
Esheun te kaa ooo

Olori Orente said...

Pride is before a crash

Olori Orente said...

Anonymous orubebe
Olorun nikan lo ma saanu eee

Olori Orente said...

Beeni

Olori Orente said...

Ekaabo ma
Eje kama so ede waa

Iya Oshoronga of Blogosphere AKA Mrs Always RIGHT said...

Lol @ mo fe lo yagbe se
@ bawo ni nkan be. Omg lwkmd

Chike TEFLON said...

You are happy now 😂😂😂

Olori Orente said...

Yori yori
Ema pe oooo

Chike TEFLON said...

Kendrick's mum are Yoruba?

Olori Orente said...

Pele sweetheart mi,
Its a lesson on pride falls befall a crash

Iya Oshoronga of Blogosphere AKA Mrs Always RIGHT said...

@sexy daddy. Yes ooooo. At last.

Olori Orente said...

Amin oooo

GODMADECHIC said...

Stella you no well i tell you! Stella ala je shu!

Olori Orente said...

Olori dimokokorkus
Ema jeki inu ile yen Marun oooo
Shey e understand story yen

Olori Orente said...

Beeni Arewa

gagaga said...

@ Galore: Ori e ti gbaleee

The General's Wife said...

LMAO @ Na arapuzi Yoruba🤣🤣🤣🤣🤣

Chike Chyko!
Nna ikalili okwu ikotelu!🙌

Olori Orente said...

Ekabo momsi Kendrick
Eshey gan

Iya Oshoronga of Blogosphere AKA Mrs Always RIGHT said...

At least mo ti ri pe kosi conspiracy lati le awa yoruba kuro nibiyi. Bo ti e je pe once in a blue moon la ma ri iru post bayi. Eshe o.

Olori Orente said...

Sexy daddy eshey oooo

Olori Orente said...

Olopolo Ku itumo
Eshey oo

Olori Orente said...

Alejo omo bee
Eshey gan,mofe ka ma GBE ede wa laruge

Olori Orente said...

Aya general, modupe ma

Anonymous said...

@Saved.. Ka da fueh


Unam ikot ,OLOBO 10koboYour head no tell you say Na "Hear" Abi wan write, no be "heat "OLOBO townKaSU @Saved

@ANONYMOUS ORUBEBE

Sharon Aminu said...

OK
Mo ti gbo

Olori Orente said...

Oremi adupe ooo

Olori Orente said...

Oremi one Nigeria
Modupe ipe onife ede wa

Olori Orente said...

Pride is before a crash
Itumo niyen

Anonymous said...

Bikonu ogini by this? My eyes are paining me abeg. Can't even pronounce one word sef...... Odikwa risky ooo. Am out

Mama Rere said...

Aa da fun yin o Olori Orente. Gbo gbo ton pka yin lekun, Olorun Oba afi pka yin lerin ayo.

Olori Orente said...

Diedie ni OMA mo

Olori Orente said...

Lol abi
Kasha ma so ede wa nu

Ola Yemi said...

Stella o serious ooo.

Anonymous said...

You're a real clown 🤡....sdk rocks...

Bv jatz

Be still said...

Nice one. Head wan knack cos I read am back to back. It's worth it though. Keep it up Orente

Anonymous said...

Hahaha! TGW it's ose pupo, this one you write is Yoruba in Igbo language

Anonymous said...

Ki ni eleyi bayii?

Betty Promise said...

Ni bo!....Oyaaaaaaa!!!!!
Shey alafia le wa eyin befeeee's(bv's)lolzzzz

Anonymous said...

Oloribuku orubebe oshi, omo ale jati jati, abiipabe

Anonymous said...

Yoruba ni ede ti olorun yi o fi se idajo aye, iwo ti ko ba gbo ti e ba e lojo idajo niyen o, ki olorun ma ni ki owo paradise ki o lo ro pe ina lo pe. Olori orente o ti ri orun wo. Ori e wa nibe

Olori Orente said...

Amama shey ni gbogbo igba
Tie EBA ni suggestions ,ki a Jo so

Olori Orente said...

Amin ooo Jesu
Mama rere emape funwa

Bee10(mummytwins) said...

Sdk ma pa wa pelu isó atî igbè

Olori Orente said...

Oya kalo

Bee10(mummytwins) said...

Laye kó si nkó to má jobè
Won tî bi wan da

Olori orente Ku isè o

stella dimokokorkus said...

Mom binu gan. Awon mi ko ki mi pe STELLA Eku igbe

Anonymous said...

Hahaha... @Orente... Mabinu si mi.... Hear mo Feh kor


@Gagaga... Oniranu, OLOBO townKaSU
@ANONYMOUS ORUBEBE

Ikuenogbon Boladale said...

BV Orente, E seun gan o. Mo gbadun itan yii gan ni.

Anonymous said...

Hahahaha... I no even read am... I don't know how to read it... But I love itI be barracks person, so I picked few Nigerian languages
@ANONYMOUS ORUBEBE

Anonymous said...

Lmao!! Stella o gbadun rara

Anonymous said...

Bv Olori Orente, eku laakaye mode gbadun Itan yi gan ni

Ajoke said...

Stella o se gidi gaa

Ajoke said...

Olori orente ose gaaani o.

Mama Rere said...

Lol Stella eku igbe yi ya oooo,idi a tura ooo

Shirley said...

Bv orente ese gan.eku iroyin

Shirley said...

Galore Enu e o da rara,lolz

Shirley said...

Same boat,but I dey try for writing.

Iya Oshoronga of Blogosphere AKA Mrs Always RIGHT said...

Welldone sexy daddy. You tried jare. Lol. Sugbon oloun nikan lo mo nkan ti e ko yi.

Shirley said...

Hahhhahhaha chai u no go kill person. Katu ki e lori egbe?tor mo no.....

Anonymous said...


Eku ise opolo, eyin omo kaaro ojiire.

Igberaga ko dara, aseju ni baba asete

Priceless Jewel said...

Beeni, oku opolo!
Omo Edo lemi oh😂😄😅😘😘😘


... Jesus is my worth!

Priceless Jewel said...

A wa, eleleleleelele a wa oh 😂😄😅😘🎵💃💃💃👏👏🎶🎵


... Jesus is my worth!

Priceless Jewel said...

Iya oh! Owo meji fun eyan kan!😘😘😘💃💃💃👏👏👏. Iya arogba aso ma ba le!


... Jesus is my worth!

Mrs A said...

Adeola oshey gan
Mogbadun itan yi

Priceless Jewel said...

O trirai gaan OmoBee!😂😄😘😘😘👏👏


... Jesus is my worth!

gagaga said...

@Galore: A fi olobo tankansu naa. Oloko tankansu nii mi.Were alasho.

Priceless Jewel said...

@ 13:56; Ko ye mi oh! 😂😄😅


... Jesu ni worth mi oh🤣😂😄😂😄

Anonymous said...

Pride goes before a fall!! Not crash..kmt!

Iphie dearie said...

I think I know what 'lati' means.lol
My interpreter isn't close by todayyy ooohhhh🙆🏽‍♂️
Lobatan!!!

Emmy said...

Eseun Olori o..agba o ni tan lorile o. Lotito,igberaga lo n siwaju iparun. Eni ti aye ba nye loni ko rora,obiri ni aye,to baa fi siwaju atu fiseyin. Iwa lewa omo eniyan.

Maria K said...

Eyin eyan mi, se dada lewa. Mo n gbadun yin losan yi. WaSe oriire olori orente. Bo tie jepe mo pe de die. Olorun a saanu wa laye buhari yi oo.i don Taya abeg

jelly said...

Oda ju

Kendrick's mum said...

Chike am not oh African magic yoruba did it's magic oh.....lol. I missed d Igbo post yesterday.

Kendrick's mum said...

Stella o funny gan!

E'pele o @ release fart

President D'Royalty (Stella's Original Blog Bff) said...

Oya, e y'ago lo na
Emi Diroyaliti, aare gbogbo alejo bulogu Esidike ti de

Olori Orente, skelebe, omo Yoruba atata, itan re yi dun, gbongbon kan si. Se iwo lo poo papo ni abi o jii gbe?

*ojoko o k'ese l'eri arawon pelu koboko olojumeje lowo*

*eni t'oba tafelefele t'obe bi oya labe komenti mi ajegba*

President D'Royalty (Stella's Original Blog Bff) said...

Ikwakwakwakwakwakwakwakwakwakwa
Moku ooo

Koboko elenu meje mi da?
Awon omo kan n ja n'ibi

Mama Ke said...

Wawuuuu!!!!! Olori Orente, in as much as i don't like you i doff my hat for this write up. E sa ku ise opolo. opolo yin o ni jona oo. Iwa pele lodara julo.igberaga man gbeni sanle ni.

President D'Royalty (Stella's Original Blog Bff) said...

Ikwakwakwakwakwakwakwakwakwakwa

Baba kekere, Ojuigo, ede wo leko yi?
E fe fowaloju ni?

Uberhaute| +234 8151914305|Beauty Therapy| Sales n Services said...

E kú isé.

1. Àmó kò sí ohun tí ó n jé 'yanga' nínú èdèe Yoruba.(there's no word like yanga in Yoruba language)

2a. Ohun (fún ohun tí kò l'émìí) (for non living things)

2b. Òun (him/herself) (fún ohun abèmí)
👏👏👏👏

Anonymous said...

My Yoruba sucks. Make I waka pass

Olori Orente said...

Haaa mama ke kini mo shey oo
Mi kin ja oooo,jeje lomo eko nlo
Timba to seyin so eyin ejor emabinu faaa
Eshey gan
Irepolodun ooo

Olori Orente said...

E tii peju
Ekabo sori eto
Olorun ama yo wa oooo

Olori Orente said...

Esheun gan
Eje kama GBE ede wa laruge

Olori Orente said...

Ekaabo sori eto

Olori Orente said...

Ajoke kaabo sori eto yi ooo

Olori Orente said...

Opolo gbogbowa oni joba

Olori Orente said...

Esheun ooo

Olori Orente said...

Emi koni mo ko Itan yen oooo
Mokoro wipe ako gbodo je ki ede wa Ku lailai
Mojuba eni to ko
Mode dupe lowo olori korkus toh bawa GBE sita

Ema jeki ede wa Ku
Eni ti oba ni nkan mi ta ma jiroro ka GBE wa sori tabili
Inu mi dun gan wipe gbogbo awa omo oduduwa LA fowosopo
Olorun ada wa sii ooo
Inu wa yio dun kaale
Eje ka GBE EDE ati ASA wa laruge
Eshey gan ni ooo
Ire ooooooo.

Anonymous said...

Eku igbe kor,eku ito ni,onimu reluwe.

Anonymous said...

Eku igbe kor eku ito ni,onimu reluwe.

Aidearest said...

@ Stella, e Pele ma. Se iso yen ko dun yi ni idi? 😐(I hope d fart no pain u for bum. Na so we dey greet elders wey fart. Lola)

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...

Advertisement