Stella Dimoko Korkus.com: ORIKI IBEJI....

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, 20 December 2017

ORIKI IBEJI....

Awon eyan mi...kilon sele?..emi ni Stella lon soro....
Ama rira inside the post..hahahahahhahahaha


ORIKI IBEJI {EJIRE}


Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.
Ẹdúnjobí,
Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi,
Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,
Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.
Tani o bi ibeji ko n'owo?
Emi ooooo


Dedicated to all the Ẹ̀jìrẹ́s
Aku ipalemo Odun oooo
Abawa laye,ayo lama fi shey ooo


Bv Olori orente

47 comments:

Miss Ess said...

Winiwini loju orogun, o so ile alakisa di onigba aso.....emi wa a se pupo e

Rowland said...

Olori Orente, Iya Ibeji. Mo ki yin Ma. Emi ni Rowland, Ema se iyonu, e wa ninu adura mi. Ema gbagbe pe Mo nife yin gan. Eyin ati Omo Iya mi Mummy Twins Bee 10 ati Sharon Aminu.
Ninu odun tuntun yi, nkan ti e fe olorun Ma se fu n yin. 💝💝💝

Dada Toyosi said...

Okan nba bi,meji lo wo letomi,tin ba bejire,inu mi aaadun oooo,eni bami bi beji kodi de joo,tentere

Yori Yori Princess Loveme Jeje said...

me bu omo oduduwa ni eko oni baje

THELMA'S CAKE WORLD said...

Tiri gbosa fun gbogbo ibeji to n be ninu blogu yi...
Sdk, tuale fun yin o...
Gbogbo ololufemi tin be ni yi, eku igbaladun..

Olori Orente said...

Amin jesu

Senator EsE EsSAy said...

Sun re o baba mi. Okunrin takun takun..... Keep Resting in peace my humble,hardworking and loving Dad. A friend spelled for me tho

GOONs Mi said...

*Eyesrolling*

Anonymous said...

ko easy lati to ibeji.
Sugbon ti won ba dagba tan, won a MA dayan lorun

sugar babe said...

Awon goons mi,ekwu igbadun,ekwu odun,adafu gbogbowa oo"asheee"hope I did not murder Yoruba Lang?

Adadioramma said...

Bawoni o...sewapa.
Ngwa ka odi

Lady Bug said...

Okan nba bi
Eji lo wole to mi wa

Olabisi Evelyn said...

I just recited it to my 9 months identical twin girls, Rinsola and Rinsire thanks for choosing me as your Manama, I love you scarra, twin baby dust to all ttc

Chike TEFLON said...

Olori Orente talo nsoro?
Mi obo ooo.
Kile WI?

Olori Orente said...

Hahahhahahha Stella oooo
Ekasan gbogbo ile
Aku ipalemo Odun oooo
Nkan Ayo oni wan Nile wa ooo
Olorun apese gbo ini wa oo
Awa ta toro ibeji, olorun afunwa
Amin.

Cynthia Iyede said...

Awon ejire ni iyanyi, e n'le fa! hehehehe

Magnificent Mo said...

I just recited it to my precious twin in Ma belly. I am patiently waiting for nine months to behold my King and queen. Emi gangan ni iya ibeji to be.

Anonymous said...

Ejire, Ara isokun
Okan MO bere
Eji lowole tomiwa
Owole alakisa so alakisa donigba aso.


Tayelolu igese oni gba oko.

Mz Poundz said...

ibeji wunmi ooooo
ibeji ni oga mi (twinsfaja)
Olorun funmi ni omo meji bi o
amin

bv olori orente...ibeji is your portion
bv bee10, Sharon aminu & all GTC women.. Olorun ti sign si twins yin


Foodie said...

Alagba Rowland, Eku ipalemo odun

Scarlet Gruber said...

ejire ara isokun. oriki nla, emi naa fe bi ibeji o. aku imura odun. emi wa ase opolopo e o. amin.

Foodie said...

Inu mi dun pupo pupo leni. Oluwa ema se oo.

Olori Orente said...

Awwwww Omo iyami Row Rowland
Amin loruko jesu
Emi Na nife re pupo
Adura waa magba....amin😘😘😘😘😘😘😘😘

Olori Orente said...

Beeni,won man rewa tobadagba tan

Olori Orente said...

Awapa ooo

Olori Orente said...

Amin ooo, Omo iyami
Bosemari niyen😇😇😇😇😇

gagaga said...

Ejire, ara isokun
Edunjobi, okan nba bi, meji lowole tomiwa.
Ebekishii, bekeshe,
O beee sile alakiisa, o soo alakiisaa di oni igba aso.
Winiwini loju oroogun, ejiworo loju
iya ee.
Buu mi kin baa e rele, yin mi kin pada leyin ree.
Obaa omo. Afinju omo to n gba ikunle iya. Won a tun gba idobale baba won. etc. Hmmmm....how I love you guys.

Dada Toyosi said...

Allahumo amin

Anonymous said...

Amen

Minnie Rexpect said...

Mo kin everybody nibibai. Lol..hope i tried? My Yoruba is next to nothing. I don't understand nada of what you wrote buh I guess you're hailing twins. Since I'm a twin I collect the hailings too...lol.
God will do yours in a while just believe.

ThatYorubaChic#wifenotcook said...

Olori, eshey fun eleyi naa

ThatYorubaChic#wifenotcook said...

Olori, eshey fun eleyi naa

SHAKITI BABY said...

Olori Orente....Iya Ibeji.
Oriki ta ma ka fun a won ibeji yin lodun to n bo niyi loruko Jesu.

Olori Orente said...

Ekabo omo iya

Olori Orente said...

Haha haha ogbiyanju pupo

Olori Orente said...

Oso alakisa donigba aso

Olori Orente said...

Amin Jesu
Mofi rinsola ati rinsire toro lowo eledumare

Olori Orente said...

Hahahhahahha
Chike ooooo😀😀😀😀😀😀

Olori Orente said...

Amin
Were lamagbo
Ire naa akari

Olori Orente said...

Amin
Asopolopo laye

Olori Orente said...

Ogbiyanju
Amin loruko Jesu

Anonymous said...

Epo be ewa be o
Epo be ewa be o
Aya mi o Ja o ye
Aye mi o Ja
Lati bi ibeji
Epo be ewa be o
Singing.....

Bunmi Kenny said...

Thanks orente! Na twins i be. My head dey swell weneva i hear this oriki!

bravitudegal said...

Ejire ara isokun. Ejire ni baba mi, emi na si fe bi ibeji nitori omo ogbomoso ni mi, ejire si po pupo nilu WA. Olori orente ese pupo

Olori Orente said...

Awww ibeji ni iyami naa
Omo ogbomoso naa ni
Adupe oo

Olori Orente said...

Ekabo
Monife ibeji gan

Olori Orente said...

Amin ooo jesu

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...