Stella Dimoko Korkus.com: Orishirishi Ounje Nile Yoruba

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, June 20, 2018

Orishirishi Ounje Nile Yoruba

Ounje Yoruba ma dun gidigan



IKOKORE


1.LAFUN:

LAFUN JE OUNJE TO WOPO JU LAARIN AWON ARA EGBA .ONJE OKELE NI LAFUN JE AROMORA SII NI PELU.A LE FI ORISIRISI OBE JE SUGBON OBE TI O TAYO JULO PELU RE NI OBE GBURE OLOBORO ATI ERAN TABI EJA A SI LE FII GBONMO GBE SOFUN.



2.IYAN:

awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje to gbayi julo nile Yoruba.isu lama gun felefele ninu odo titi yo fi di iyan a le fi isapa je tabi obe egusi sugbon obe to tayo julo ni obe efo elegusi tabi riro ki a wa fi eran igbe de lade. a le fi emu ogidi sin losale.



3.SAPALA:


sapala elepo he okan lara ounje Yoruba ,o jo moin-moin pupo sugbon agbado pelu ata ati epo pupa ni a fii ma n se sapala.awon elomiran a maa je lasan awon miiran a si ma mu gaari olomi tutu peli re.



4.IKOKORE:

Ikokore je ounje to gbajumo laarin awon ara ijebu.isu ewura ,ata,epo ati awon eronja bii ede,eja la ma fin n se ikokore yii a si le je pelu eba tabi okele tomba wun nii.



5.EBIRIPO:


Ebiripo je onje to se koko fun awon ara ijebu.isu koko ni a ma fi n se ebiripo a sii pon sinu ewe sori ina bii eni pon moin-moin.obe eyikeyi to ba wuni nii na fi n tii sonafun.


6.ASARO:


Asaro elepo je ounje to gbayii laarin gbogbo omo ile kaaro-o-jiire.Ako isu pelu epo pupa ati ata,eja ni a maa fi n se Asaro .aropo sii lama fii se ni ori ina.a le fi omi tutu tabi oti olomi osan tee lo si ona ofun.


7.EGBO:

Egbo je okan lara ounje ile Yoruba.Agbado funfunni a o se lasero petepete.a le je pelu ata dindin tabi ki a fi ororo yii pelu ewa aganyin.


8.OFADA:

Ofada je iresi ile Yoruba ti o sii maa n muni
datami.ile Yoruba nii a ti n gbin a sii ma se bii eni se iresi gangan.Ata dindin to ta lenu sue-sue pelu awon eronja bii igbin,eja gbigbe pelu eran tabi ponmo dee lade.



Ewo Lani ife si julo ninu won??

Olori Orente

85 comments:

  1. Olobe lo loko leleyi o olori orente.

    ReplyDelete
    Replies
    1. I love asaro elepo. The taste is divine.
      Weldone olori Orente

      Delete
    2. Sokoyokoto😀😀😀

      Delete
    3. Iyan ati efo worowo pelu opolopo ede pupa, eja gbigbe, eran lorisirisi ati iru wooro a maa ladun pupo

      Delete
    4. Olori Orente, emi a maa je Jogi, Mosa, ojojo, Egbo, adalu ewa, efo elemi meje, obe dudu, Eko ati bee bee lo

      Delete
    5. I don't like ikokore but ofada is bae anytime any day

      Delete
    6. I love love love ikókóré and èbìrìpò,our favourite food from my precious state,i'm a great jebusite/Fulani,mixed tribe.What is Lafun and Sapala?I couldn't read the write up very well cos there is no àmì on it but nice write up though.
      Anonymous Bug

      Delete
    7. Check out ikokore_ on instagram and thank me later

      Delete
  2. Someone should please read and translate.

    ReplyDelete
    Replies
    1. She's telling us about different foods the Yorubas in different state love to eat like Amala, Pounded yam, Ofada rice, Pottage, Porridge etc.

      Delete
    2. Wednesday, June 20, 2018
      Orishirishi Ounje Nile Yoruba
      "The Yoruba bread is sweet




      FREE


      1.HIP:

      I LOVE YOU TO REMEMBER THE OTHER MEMBERSHIP OTHERS THAT I HAVE BENEFITED WITH THIS MEMBERSHIP. WHEREAS THE RESPONSIBILITIES OF THE MEMBERSHIP REQUIRED THAT THE JUDGMENT OF THE JOURNAL ORIGIN OF ORIGINAL OR WARRANTIES OR REQUIRED HOW TO READ MORE.



      MODERN:

      Yoruba people say that the famine is a dangerous cat, and it's about to escape. ... Yes. We get from our ancestors and it is the cheapest food in Yoruba. The lush tortoise in the river until it becomes dry can be scorched or fried egg but the sweetest sauce in the pebbles or crows comes add lacquer meat. This is what the Bible says.



      3.SAPH:

      Pumpkin is one of the most common food in Yoruba, it is very fun but garlic with red pepper and red is being used as a non-other. .



      4.Young:

      Unconcerned foods are a popular food among different kinds of hazards, peppers, oils and societies, as well as fish, and this fish can not be cooked or eaten by the rabbit.



      5.EBIBRIP:

      Grooming is a very important diet for the body of the body. It is usually used as a replacement and is embroidered in the greenhouse on the fire as a focal point. Anything that is so appealing is very encouraging.


      FIRST: Cultivation

      is a common ingredient among all indigenous people. In coconut with red oil and pepper, fish are usually cultivated. It is more common in the flames. We can water cold or orange juice go to her own.


      7.Express:

      Eating is one of the Yoruba foods. The white potato is well-researched. It can be cooked with pepper or sprayed with oil.


      8.With:

      Of course, it is a
      poisonous poison in the Yoruba population. It is Yoruba that we are cultivating it and it does not matter exactly what it's like. It's a long way to try it with some tips like snails, fish with meat or soup. write lade.



      Whose love is the greatest love in them?

      Prince of Orente"

      That's the translation according to my phone😅😅😅

      Delete
    3. Hahahaha
      Kidjo o ti gba penalty lo throwing 😀😀😀

      Delete
    4. Na real translation

      Delete
    5. Poisonous Poison bawo kidjo?

      Jowo mura si ise Mamalawo ti o moo se. Ma fun wa ni majele je.

      Olori Orente, ku ise takun takun.

      Delete
    6. Ageless T, LMAO. Na real mamalawo.

      Delete
    7. 😅😅😅😅😅
      Ageless T, don't mind my mischievous phone o jare🙈🙈🙈

      Delete
    8. For some minutes i was applauding you, when you now said your phone translated it
      😂😂😂😂😂😂😂

      Delete
  3. Pepper just entered my eyes as I opened this post.

    *screams for water*

    ReplyDelete
  4. Ok I have tasted all the foodie very sweeties..

    ReplyDelete
  5. Iyan ati Ofada nikan ni mo nife si ninu gbogbo won. Mo k'orira Ikokore ju igbe lo. Koda Asaro, Ebiripo ati Ikokore maa n dabi igbe loju mi iyanma

    ReplyDelete
    Replies
    1. I changed to English so I can get the meaning and it translate ofada as WITH no7 as express and others with I don't understand .does it mean Yoruba no get English meaning

      Delete
  6. LMAO People don't read this in google translation. I died laughing hahhahaha

    ReplyDelete
  7. Mo nife iresi ofada gidi gan mo si ni die nile pelu, mo ma n dinta si pelu opolopo epo pupa ati iru woro. Olori Orente o gbiyanju gidi pelu akosile orisirisi ounje yi... O dami loju wipe oko re yoo ma je orisi ounje aladun nile. Egba meji kii jara won niyan, Egba lemi naa ti wa.

    ReplyDelete
  8. Nice one Olori Orente. Eyi ti mo nife si julo ni Ofada ati Iyan. E she pupo.

    ReplyDelete
  9. Yepa! Come see me salivating here

    ReplyDelete
  10. Emi nife si Iyan ati obe egusi gege bi omo Ijesha rere ti mo je. A ma n jiyan ni owuro, osan ati ale.
    Leyin Iyan ni lafun. O je okele ti o yara la ti se. Obe gbegiri ati ewedu ni mo fi n ma je lafun.
    E ku'se takuntakun iyaafin Olori.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ehn ehn...sepe omo ilu iya mi ni prudent.
      Omo ijesha ti o ridi isana, ile ni omo owa ti n muna roko.

      Iyan ati egusi tabi efo riro ko LA fi we

      Delete
    2. Ara ile tiwa oja
      Ekasan eyin temi

      Delete
    3. Beeni o Elegant. Ijesha ni me e re. Ori mi a ma wu pupo ti mo ba gbo oriki Ilu mi. E seun gan lopolopo

      Delete
  11. Olori Orente..e ku ise ma. e mi o nife lafun oo.
    elubo isu ni no nife si. Iyan ati efo riro, iresi ofada ati at a dindin elemi meje 😜

    ki lo n je sapala??

    e ku ise oooo

    ReplyDelete
  12. Emi o like ikokore tele tele, but moti bere like e die die😁😁
    Mo like isu gan, so asaro dun mi gan gan. Mo like pelu iyan sugbon the big belle no be here😅😅😅😅
    Emi o like ofada tele but mo je ni Keresimesi to koja pelu ayamase! Chaiiiiii😋😋😋😋 I must be multilingual by force. At all at all na im bad pass😂😂😂

    I hail all my naija people on. Every tribe matters👍👍👍👍

    ReplyDelete
    Replies
    1. Erm...this one pass me o🤔 #head-scratching emoji

      Delete
    2. Hahahahaha.....I am saying you tried 😀😀

      Delete
    3. Ah..okay. Thanks 😅

      Delete
  13. A tun le pe sapala ni abari

    ReplyDelete
  14. I love yoruba foods...the more pepperish the better 😆 and I make the best ikokore ever 😋

    ReplyDelete
  15. Monifesi Iresi Ofada . lopolopo igba ni mon manse fun oko mi. Omo egba ni oun nan de nifesi

    ReplyDelete
  16. kare olori orente, ani opolopo ounje aladun ni ike Yoruba, lara won no abari,to w/o nd I agbada ,expo,ait ata se,ojojo, isu gbigbo no won fi n din,ekuru naa o gbwyin
    a dara fun o,olori

    ReplyDelete
  17. Olori Orente e Ku use jare..

    Ha! E mi mu ranti egbo, igba to mo wa in ile iwe mefa ni mo ti he gbeyin mi o de mo n se.

    Mo ni fe ofada gidigan ati asaro( ka sa sope gbogbo ounje to a le fi isu se).
    Mo feran iyan gidigan, oko mi na si feran re, ti mo ba fe ko she nkan funmi tabi ti no fe wu Lori ni mo ma n guyan.

    Olori booya ti e ba Raye ki e she eto Lori obe orisiirisii.

    ReplyDelete
  18. BlackBerry ata ko se ni kosi oju 're,toju bole eran iya Nuru,nigbati kiise roo oko ati obo ni a n so,mi o mon nkan ti o wa debi

    ReplyDelete

  19. In ma gbage-e o Ijesha, Omo Owa o Ijesha, Omo Eleni ate iika, Omo Eleni Ewele.
    In pele o gbogbo eyin Ijesha, Omo Ogedengbe, agbogun gboro, adi pon pon l'oju ogun,
    Npele o gbogbo Omo Ujesha, N'ile, L'oko, L'ona Oja, Emi Omo Owa ni Mo mi kin iin o, Aa kere Oko d'ele o!!!

    ReplyDelete
  20. E Ku use takuntakun.

    Akiyesi mi no one ebiripo, kii SE ounje Ijebu, Remo lo Ni ebiripo.
    Koda, ara Ijebu miiran ko no Ogun to a n PE Ni ebiripo.
    Lafun Ni mo korira ju, oorun re Ni mo korira ju, Lati kekere.

    A dupe fn Olorun to o fun way Ni aeon ounje mere-mere yii Ni ile yooba.

    ReplyDelete
  21. Mi o je sapala ri o

    ReplyDelete
  22. Ekasan omomi, omodada Olori orente, esegon for this😅😅😅

    ReplyDelete
  23. Despite the fact pe Omo Igbo ni mi, ni igba ti mo loyun, amala ati ewedu ni ounje ti ko je kin throw up. Mi kin fi ounje yen sere rara. Ata yen gan gan ni koko...

    ReplyDelete
  24. Olori Orente, e jowo e se alaye fun wa, bi a se nse obe isapa ati sapala. E seun

    ReplyDelete
  25. Olori e ma ku ise oh...

    Mo nife ofada iresi ati Asaro elepo pelu ogunfe... 😁

    Awon Ounje Yoruba ma dun gaan sugbon ata maa poju...

    ReplyDelete
    Replies
    1. ata yen gan ladun ibe.

      o ti mu mi ranti ogufe o. sugbon Moti ra eran pupoju pamo sinu freezer. O nwu mi je gan bayi

      Delete
  26. Olori orente, kuu'se. Mon feran iyan pelu obe efo riro. Ti a ba fi epo pupa se efo riro, ti a we ata si tia ko je ki ata ko kuna, ki a wa ya eran igbe si, pelu igbin ati ede, pelu eja gbigbe. Oluwa o... ki iru woro o maa sere ninu re, yepa! Ki eyan fi eleyi je iyan to kun'na daradara. Chai! Yoruba dun.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Omo yòòbá ponbele ni è. Mo ni fesí akajuwe rè👍👍

      Delete
    2. Ha ori e pe gan ni. Ki eyan ri iru iyan ti o juwe yi je. Aye re a ma dara o. Mo nife si egbo na, amo mi o ri ra ni ilu eko yi. Egbo pelu ewa aganyin ati ata dindin ti o kun fun orisirisi tinu eran o ma'am dara gan o

      Delete
  27. Mo ni ife asaro elepo kpukpo...ati atarodo.

    ReplyDelete
  28. Scarlet Gruber20 June 2018 at 17:13

    olori orente, mo gba fun e. eku ise opolo. iyan ati obe isapa ni mo feran julo, sugbon oseni laanu pe isapa ko seri ra bitigba kan mo.

    ReplyDelete
  29. Iyan ati efo elegusi, ofada ati asaro elepo rede rede ni moni Fe siju Ninu gbogbo ounje yi.ku ise opolo olori orente

    ReplyDelete
  30. Ofada ni o se ohun gbo gbo 😂😂
    Obe Ofada pelu eran orisirisi ni a je ju ni ilu Germany. Okan dun mi ni pe epo Togo ni won tan nibi. Awon oniyeye ko ni je ki a gbe epo wo inu oko ofururufu. Oma se o

    ReplyDelete
  31. Olori Orente ishe le'she sugbon ko si ewa ati agbado nibe....hahahaha

    ReplyDelete
  32. Olori asaro elepo rederede pelu eja tutu ninu re ni mo feran

    ReplyDelete
  33. Moyinoluwa Adebanji8 March 2023 at 18:02

    I love it

    ReplyDelete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141