Stella Dimoko Korkus.com: Blogging In Yoruba - Eku Awon BeeFee's Oh!!!

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Thursday, March 10, 2016

Blogging In Yoruba - Eku Awon BeeFee's Oh!!!


Awon Bee Fee's Eku Ojo Kerin Ose .....





Mo fe ka jo f'inu po nu ni ede Yoruba ki a de si mo ipe ebi kan ni wa ki a de je ki ife gbo o roo si.

Mo ki gbogbo yi bi ese n so nnkan ti e n so.

Awon irumole Yoruba nko? Se e wa dada?

Ife kan.

kikikikikikiki..Ejo,ema so pe yoruba mi ko correct oh,Emi na omo Eko gaaaaan



308 comments:

  1. Ehen ndi ofe mmanu people enter

    ReplyDelete
    Replies
    1. Where are all the ofe mmanu people?
      They've crawled back to their cave. Dry post...





      Igbo amaka

      Delete
    2. Stella, ori e ti gbale o.
      Se aworan toye kofi se apejuwa awa olorire ile Nigeria niyen.

      Sugbon eniyan daada nie. Omo olorire. Wa jeere ise owo re loruko Jesu. Amin.

      Delete
  2. Yes o! Mo fe dobo! Dunno d meaning o

    ReplyDelete
    Replies
    1. I want to FUCK.....pls FUCK me pls...

      Delete
    2. It means good morning
      When you wake up tomorrow just go straight to anybody and tell them that statement .
      Note, it's only an hunble person that can greet someone with such statement and am sure you are very humble. Am I right?

      Delete
    3. Ewwww blackberry! Lol...btw so proud of arami cos(lols) mo le kaa awon oro yen pelu pe won ni ami....yehhhh! Hahaha

      Delete
    4. LMAO! BlackBerry! I wan fuck na the meaning. U bad gaaaan!

      Delete
  3. Awon werey!!

    Oloshi!

    Afi comment naaa.

    Oni dafun anybody!!

    Kikikikiki

    #WhiteDiamondOut

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ehn ehn
      Mo mor pe opolopo yin ogbo ede yi sugbon egbo gbogbo ebu yoruba. Odaa kontinu

      Delete
    2. Hahaahahaha

      Obo ni e!:You are a Monkey.
      Mofe je rice:I want to eat rice.
      Taani?:Who?
      Mo mgbo:Aya m coming.
      Ojukokoro:Long throat
      Kilo wi:What is it?

      I love Yoruba language eh.pity I can't hear and speak it.

      Delete
    3. Kileleyi ko?
      Ko kin se dandan ke drop commenti.
      E sun si waju joor.

      Delete
    4. You cray..
      Those are swear words ooh.

      Delete
  4. Hahahaha.. Stella has killed me. U r asking after the gods!! Kikikiki. Dem dey shrine.

    ReplyDelete
    Replies
    1. I just saw d part too!!! Irumole biibo stellaa! Hahahaha

      Delete
  5. i missed the inyamiri post, now its masu kwalokwalo...remaining aboki post..ekaso...oshe...odabo

    ReplyDelete
  6. Lmaooooooo...... This stella will not kill somebody aswear

    ReplyDelete
  7. Oluwa a fun e ni mo.oluwa a wa pelu e ni igba gbogbo.

    Omo iya kana ni wa ati hausa ati igbo.


    Mc pinky

    ReplyDelete
    Replies
    1. Mc se ori komenti mi nigbakan
      Moo ki e oda mi lohun
      Mo ni oluruko egbon mi nie
      Oruko e mejeji

      Delete
  8. Awon igba irumole ki e Stella ...... Ede Yoruba dun yungba yungba o larinrin

    ReplyDelete
  9. Replies
    1. Oko oloko, Abi ti tie? Adugbo WO lo wa ni eko?

      Delete
    2. let me come and FUCK...u

      Delete
    3. Wa je kin do e pa la leyi.. wa fe ku

      Delete
  10. Oga oh, yoruba yi fe pa mi. Ase yoruba mi ko ti e le.

    ReplyDelete
  11. egbami oooo
    iku re ooooo
    omo Igbo ni mi
    but Yoruba noni

    *Sips Hennessey from a platinum chalice and adjusts concave lenses*

    ReplyDelete
  12. Hahahahahahahahahahaha,stella dont even try this your blogging in birom or efik

    ReplyDelete
  13. Hahahahaha...mi o le rerin o. SDK ti fe pa mi o. Ni tooto, omo iya kan naa ni gbogbo wa. Mo gbe gbosa fun yin o, anti Stella, ise le se pelu yoruba yin. Awon irunmole wa o, awon bi obatala, osun, sango ati beebee lo. Eni a dun, a si larinrin. Gbogbo eyin omo Odua, eyin omo kaaro oji re, e nle o. Se alaafia ni o?

    ReplyDelete
  14. Hahahaha...
    Stella,has murdered ndi ofe mmanu's dialect for them...
    Well,apology accepted on their behalf...
    Am happy you did this cos they wanted to die of hate yesterday...
    Ebi ni pami jare...make I go chop !...

    ReplyDelete
    Replies
    1. Linda, ki lo fe je? Oko Abi obo Abi ounje!? Lol

      Delete
    2. No mind them. To comment them no fit. Does this mean more igbos read this blog than yorubas?

      Delete
    3. Tribalistic idiot.....

      Delete
    4. Ala so ja mu le le yi Oo
      Ko seni ti olorun ose fun jare

      Delete
    5. Gbogbo wa lamo wipe idile elebi na loti wa

      Delete
  15. Taa bu obochi ndi ofe mmanu.
    Ndi uchu!
    Aga m ehi ebea!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ndi Uchu indeed!!!

      Delete
    2. No time to lick ass.10 March 2016 at 14:45

      Shut up portable vivian, why the unnecessary insult?

      Delete
    3. Iwo to ma n yin ibon enu naa n ke?
      Olorun a fun e ni alaafia. A ma pa e ki o to fi ibon pa wa.

      Delete
  16. Let me read comments with my google translator


    Rolex chick over to you.

    ReplyDelete
    Replies
    1. You get time. Stella just dey find my trouble.

      Delete
  17. Egbon wa, Iya Dimokokorkus, dada ni a wa, eku ise o, Olorun a ma bukun yin. E je ki ise rere ma te si waju o.

    ReplyDelete
  18. The pix above is that of a typical yoruba woman

    ReplyDelete
    Replies
    1. Buzz off, this post is not for you. Omo ti wo ko ni ile.

      Delete
    2. Oponu aye rada. Mo mope bi iya e se ri niyen. Ako igba omo kekere

      Delete
    3. Awonran ponri igba iyalaya e niyen. Olofo.

      Delete
    4. Awon oloriibu meji to wa loke yen ni. Epe lo ma pa won gbeyin.

      Delete
  19. O ti e han lara e pe omo Eko ni e..

    Jo awon irunmole ewo o?

    Nnkan to se pataki ju ni Ife to daruko yen, olorun a fun wa ni ore ofe lati ma gbe ninu Ife.

    ReplyDelete
  20. Lol..Stella shey Yoruba looko yii?? Taloko e? Ekasan ooo

    ReplyDelete
  21. mi o le rerin ooo, yoruba re idi baeed gan
    kakakakakaka!!!
    sitellaaa o fe ki a finu "ponu" ke?
    o fe ki a di oponu niyen
    rather mo fe ki a finu konu is better
    one loofu oooo

    ReplyDelete
    Replies
    1. Finu ponu is correct. It's a dialectical change....lagos yoruba is different frm osun/oyo or ijebu. Stella is right,ure also right

      Delete
  22. Mummy Micheal, se gbogbo e dun? Aku ipalemo ose o,e ba wa ki daddy Micheal ati awon aburo wa.

    ReplyDelete
  23. Stella tipa mio.... Atigbo eseun pupo..Awon omo yin nko ati Oko??

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ori e ti gbale Stella I swear, irumole Ko irumola ni


      So na so yoruba people dey open mouth for ur village?

      Eku blogging sha, o try dee sha but oo pass o

      Delete
  24. This Stella na clown
    When will u bring the urhobo version
    Migwo my sisters...

    ReplyDelete
  25. Stella, Omo igboro ni e oo!!!

    ReplyDelete
  26. Haa stella yoruba re yi gidi gan ni o

    ReplyDelete
  27. Afi awon irumole Yoruba na! What Google translate will cause! Kikikikiki

    ReplyDelete
  28. OMG... tis is too funny.... ese adupe

    ReplyDelete
  29. Stella, o gbiyanju gidi gan. O wu mi lori pupo, mo ni ebun nla fun kan e, sugbon *lipssealed*

    Eyin omo oodua gbobgo lori bulogi yi, mo kii yin leyo kan-an kan-an. Se scarcity epo ati ina monamona ti nse monamona yi ko bu omi ewuro si wa loju pupo. Ki Olorun bawa tu orilede yi se, Amin.

    Mo npada bo wa ka komenti...E nle o! aaaaaaaa....

    ReplyDelete
    Replies
    1. Awa na ki yin o, scarcity noni o je ki araye type pupo

      Delete
    2. Stella,Yoruba yi gidi gann ooo.I don't even understand what you wrote.

      Delete
    3. Omolara,mo- tin foju sile fun asayan oro re,nitori wipe o je okan l'ara awon irunmole omo ile kaaro oojire ninu bulogi yi.
      Moni igbagbo wipe alaafia ni eyin eniyan mi wa loni gege bi ati fe foro jomitoro oro ni osan yi...odigba.

      Linda eze(ayaba ati oga bulogi yi).iphie ololufe(dearie),iyawo ogagun(tgw) e ma ro wipe mon bu yin ni o...hehehehe

      Delete
    4. Lol. Bitchplis, looto ni. Iwo naa so itumo nkan ti o ko ka le, ki won ma ro wi pe oti bu won nau. hehehehe

      Delete
    5. haa @bitchplis padi mi, ori e wa nbe baje... Awon Linda eze ati bee bee lo ti o d'aruko won ye, maa l'ero wipe o nbu awon ni o. O daa bee...kikikiki

      Delete
    6. Oti wa official baayì wipe Mo nìfe re lopolopo. ...#laisihomo ..lol

      Delete
    7. Bitchplis pls interprete what u people are saying na.abeg.kai see as I dey read every but no understanding.

      Delete
    8. Egbon bitchplis, se oye ketun gbe awon anti wa yi wa si ori eto yi?
      E ba si je ki won joko laye won.

      Delete
    9. Haa Bitch plis.. Iphie? Kilonsele oooh. Lolzzz.

      My fellow music lover,howdy?

      Delete
  30. OMG... tis is too funny.... ese adupe

    ReplyDelete
  31. Haha, e kuro lonan gbogbo awon inyammiri. Yoruba lo nile leni!!!


    Iya laya anybody!!!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Lol.....Ti won babo e bi era,mi o si nbe oooo

      Delete
    2. Hahahahahaha...Eesah!!...
      Eesah!!!...
      Eesah!!...how many times did I call you?...
      Stop calling igbos names!...

      Delete
    3. Lola, Eesah ti wo eleyi naa. Abi won ti bo ni. Lol

      Delete
    4. Hahahaha.
      Abi eri enu e.
      Sugbon eyin lebu omo yoruba.
      Won pe ni inyanmiri, ori e fe daru. Shior.

      Delete
    5. Queen of d blog,but you can call yorubas ndi ofe mmanu? Talk abt double standards. I'm nt yourba by d way

      Delete
    6. And ofe nmanu is what? Description? Troublesome bunch

      Delete
  32. I hope this will not be another yoruba owned blog dat will hardly get 5 comments. in all their post everyday.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Taaa,comot for here.

      Delete
    2. Eyin eyan mi, e je ki a gbadura fun omo James yi pe ki o ba Olorun pade. Anu re ma nse mi gan. O je eyan ti ko ni Iberu Olorun!

      Delete
    3. Eje ki a para po ki a gbadura fun James o!!!!

      Okuku le ro pe epe ni anse!!!

      Delete
    4. hahahahaha Anonimousi ma pa ni o

      Delete
    5. Ko gbadura fun are re.
      Alainikanse omo ajokuta mamomi.

      Delete
    6. @James...Gbe gbogbo eni e yamayama yen soun jemisi. Ta lo njeun t'aja e nju'ru? Aja lo ma je enu e yen.

      Delete
    7. Gbadura fun Jamesi bawo!? Ipadanu adura ni yen! Jamesi ti ko leko! Alai ni ironu lomo na, ati ba wi, ko gba! Egba lo Ku bayi!

      Delete
    8. Awo ti won se James ti se pa,n. Won si u ti pada ni eyin re mi o ba ni kin lo baa be ebe. Olorun ase a nu e ni to ri wipe lotoloto ni Oro re fe adura. Ki Olorun ko se Anu fun gbogbowa. Amin

      Delete
    9. Mumu money maker u no dey ever remember type all ur comment at once. Silly hater

      Delete
    10. Mumu money maker u no dey ever remember type all ur comment at once. Silly hater

      Delete
    11. Anon 14:14 adura ko le gba lori james..epe ati irandiran lon ja lori re

      Delete
  33. Eyin omo yoruba bawo ni o? sewa..in Yinka Ayefele's voice

    ReplyDelete
  34. This comment has been removed by the author.

    ReplyDelete
  35. Lol... Awon irumole ko, awon ogun ni

    ReplyDelete
  36. Hahahaha.. Stella you just butchered the language, Irumole kor orunmila ni.sugbon omo Wa noni e ko si ibi tah le ti e si..

    ReplyDelete
  37. Aunti Stella, e kasan, se gbogbo e dun, e gbiyanju gan. Awon ara Germany ko, se daada ni wo wa, se e buro awon ebi yin,Olorun a ma wa pelu yin o. Mo feran yin gan, omo daada ni yin.

    ReplyDelete
  38. Hian! Eku enjoyment! Eku hot afternoon! Eku joko! hello ndi ofe mmanu!

    ReplyDelete
  39. No time to lick ass.10 March 2016 at 13:32

    Stella and bvs soro nie? Baoni everybody, baoni roman reign, my adaorimi, ayomi, adumi, lol, Hope i got it right.

    ReplyDelete
  40. No time to lick ass.10 March 2016 at 13:32

    Stella and bvs soro nie? Baoni everybody, baoni roman reign, my adaorimi, ayomi, adumi, lol, Hope i got it right.

    ReplyDelete
  41. Mo ki gbogbo eniyan toh nmu ara wa ya ni bilogi yi...
    Okun ife wa oni ja o!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Egbami! Omo calabar lo gba ede yoruba bayi?ori mi wu si e gan.o gbiyanju

      Delete
    2. Amin o Sista mi. Se o wa pa? ku ojo meta, se gbogbo e ndun?

      Ba mi ki ile o.

      Delete
    3. Onpe kotoja.
      Mori ikokuko to Ko lana.
      Ti o ba mo itumo MIA ti mo pe iya bulogi re, o ba si beere, kinse alaye fun e.

      Delete
    4. Ashewojor, so otito, ede ko lo mu orire wu, ironu ati do omo yi ni onwa!

      Delete
    5. Haaa...omo kalaba to nso Yoruba, mewa nsele ni dunuyan!!!! kikikiki

      Delete
    6. Woooowowuuuuu!!!!!
      Omo calabar, o ma de wu mi lori.o!
      Wa gba choclate...

      Delete
  42. Kikikikiki this is just too funny... The meme

    ReplyDelete
  43. Hehehehe, ok o!
    Gbogbo eniyen so pe onijo kambe
    Wombo lombo
    Ile onijo wa le gbe....
    A.K
    Hehe

    ReplyDelete
  44. Eyin temi nipinle Ondo, mo ki yin o. Ale o bai, ale yei, ke tiri ke? Eyin ti Akure Oleyemekun, se daadaa ni o. Stellina, sho wa pa. Emi ma gbadun e gan ni o. Olorun a de ma fun e se. Eyin BVNs olorire,ko ni baje o.

    ReplyDelete
  45. Eyin temi nipinle Ondo, mo ki yin o. Ale o bai, ale yei, ke tiri ke? Eyin ti Akure Oleyemekun, se daadaa ni o. Stellina, sho wa pa. Emi ma gbadun e gan ni o. Olorun a de ma fun e se. Eyin BVNs olorire,ko ni baje o.

    ReplyDelete
  46. Asiko to lati se bebe

    ReplyDelete
  47. Mo rerin takiti.
    Irumole nikan ko.
    E gbiyanju.
    Ejo, e ma so ibi di ile digbolugi bi e se so ti awon ede keji di ile awon ashiere lanaa ti e n ko nkan ti awon ara aye o le ka.
    E seun pupo.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Chai! Omo yi ma leke gan. Mio le rerin jare

      Delete
    2. Mo- jeri e,momowipe o ma soro nipa awon ajokuta ma momi ana.

      Delete
    3. Lol..@bie e se so ti awon ede keji di ile awon ashiere lanaa..your mouth ehn..

      Delete
    4. Sunshine...o sumi o. Awon ehana gbogbo, mo rerin to s'ara.

      Delete
    5. Jesu!! O lenu bajè. ...ko si ewu fun è jare.

      Delete
  48. Moti ku fun erin! Awon irunmole yoruba, eyin da o

    ReplyDelete
  49. Moti ku fun erin! Awon irunmole yoruba, eyin da o

    ReplyDelete
  50. Stella, yoruba e dan moran! o ku die ko pe ye! Ola inu kan! Ebi kan ni wa, a de ma fi ife han ni gba gbogbo.
    Ki Oluwa bukun yin!
    I think i tried

    ReplyDelete
  51. I missed blogging in igbo yesterday. Ndi igbo, ke kwa nu?

    ReplyDelete
  52. All the Ofe mmanu people that where making noise yday..Oya its ur turn..
    Come and speak, spake and spoken it here..

    ReplyDelete
    Replies
    1. olori western union10 March 2016 at 15:23

      Gbe enu e soun, oloriburuku omo jati jati, koni Dafun e.
      Owo tofi ko comment yi, oni fi shey orire. Loruko Jesu amin

      Delete
  53. Orisa a gbe o oh.. wa luwa, ori e a kan oke. Omo dada ni e Stella. Emi na omo dada ni mi. Awon yoruba ti won wa Lori blog yi da? Oya o, Asiko tito lati fi ede wa gbe sdk laruge.. Eheheh

    Ahhh emi na gbo yoruba da da.. Abi ke? @GBG, Sunshine, and co..lolll

    @Bitchplis oya e jade wa o.

    Emi omo Oodua ni mi..

    Ahhhh I don try today.

    ReplyDelete
    Replies
    1. O tiraka jare Sisi mi.
      A kuku wa nibi. An gbiyanju.
      Bawo nise ati ara, se gbogbo e dun?
      Alale ile yoruba, agbe gbogbo wa o. Aseeeeee.

      Delete
  54. Stella Mo gbè idì fun yorúbà ee

    ReplyDelete
  55. Hahhahahhahah...aunti stella..se daada ni..o dara ki a ma soro ni ede abinibi wa...mo fi iwe atejise (email)ranse si yin..e yari lati ka .ko dara rara..inu mi ko dun si yin ooo..gbogbo awon bee fee alainise onisokuso, se daada le wa..oya e je ka gbe yoruba laruge..emi ni tiyin tooto..oluwabunmi...

    ReplyDelete
    Replies
    1. Okurin lowon be
      Obirin lowon be
      Gbo gbo eniyan lowon be
      Baye sent dalo ni
      Opo to gbabe olorun....join me

      Delete
  56. Replies
    1. Stella,irunmole's are spiritual messengers to oludumare(the ruler of the universe. I bet you wanted to ask 'bout "Yoruba demons".

      Delete
    2. HahahAhhaha
      Lucile that's an abuse o
      Hahahahahahaha.

      Delete
    3. Omo ale means bastard!...
      Jati jati means disgusted...

      Delete
    4. Ewo Linda ke! O ma gbo Yoruba!

      Delete
    5. Eleyi o gbadun Ooo
      Iro nla niyen
      O mo itumo re
      Odaa na epe lo nse Oo itumo re si ni. "BASTARD " it's "omo ale jati jati"

      Delete
    6. It means "im a very good being" So repeat after me, Lucile coconut oil seller is omo ale jatijati.☺☺☺

      Delete
    7. Hahhaaa lucile you just type insults oh

      Delete
    8. Hmmmmm, tgw, olufe Mi ni bulogi yi! Bo'ni? Awon omo re nko? Ati Baa'le re ologun Agba? Ayun re se Mi o, o se di e Timo gburo re! Gba Ami Ife Mi si o, muah!

      Delete
    9. Jati jati is nonsense.

      Ese, eku itumo aayan ogbufo

      Delete
  57. O gbiyanju gan ni stella sugbon o tabon di e. Hahaha

    ReplyDelete
  58. Lol @ Stella. By force Yoruba. Though i'm not from the west but I love this dialect.

    Eyin Omo odua, ki lo nse le? Mo fi tara tara gbadun ede yin o. E ma binu ti mo be fi gba igi o. Won bi mi ni eko, mo ka iwe ni eko, ni to ri e ni mo le so di e ti mo nso yi.

    E ki ile o.

    Choi!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Omo gidi ni iwo nitire.
      Fi number ero alagbeka re ranse simi, moni ebun kekere kan fun e.

      Adiresi mi wa ninu oruko mi.

      Delete
  59. Stella to sure,ba wo ni? Awa nan Ki e o

    ReplyDelete
  60. Stella eka aso oo
    Awon omo nko?

    ReplyDelete
  61. Ku ise opolo iyawo korkus..

    ReplyDelete
  62. O ti Pe ti mo ti n so yin.
    Ojo nan Pe leni
    E mura si, e ma soro lo
    Mo ki gbogbo yin o.

    Ori mi wu o e lagi mon (singing and smiling)
    One Nigeriaaaa!!!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Iphie omo daadaa, mo gbe osuba fun e jare. O gbiyanju, o jewo wipe okan ni gbogbo wa. Ede ati asa ko ni ki e ma jo fi owo s'owo po. Mo gba adura fun o Iphie, ori e a kan 'ke, waa ri bati se, waa ri ona gbegba, gbogbo oun ti o ba ndawo le a yori si daadaa. Oko e koni di oko oloko, awon omo e, ko ni di omo olomo. Mo respect e gan laarin gbogbo awon elede keji wa. Waa lalafia, aiku baale oro...

      Delete
    2. Hahahahahaha. Omo ajokuta mamomi tonjo jo wa.

      Delete
    3. Iwor ti e gbogbo ede logbo abi
      Ohun mi ke mi na gbo ede mewa papo

      Delete
    4. Mio gbagbo! Iphie gbo ede yoruba? Motun to ni ife re si ju titele lo

      Delete
    5. ....snd and you couldn't speak your language yesterday? Shame on you.

      Delete
  63. Gbayi joor SDK..

    ReplyDelete
  64. Eyin temi ni Uk ilu London, nibo ni ewa? Eku ise eni o!!!!

    ReplyDelete
  65. Mo ki gbogbo eyan mi😄😂

    ReplyDelete
  66. Gbogbo omo yooba mo kin yin o. Amo mo fi towotowo ki gbogbo ijesa ki o mi be lori buloogi yi o.

    Ori gbogbo wa laakanke.oodua agbe ha. Nje kamaa gbe ede Ujese laruge nibikibi ki a ba ha o. olohun atunbo maa gbadua ria. In mon je ka wa lara iyan ki onman shepe nibee o.


    Baba re agbe ooo

    ReplyDelete
    Replies
    1. Mo gbadun ijesha e bajè. Karè lai.... mè lè so jeshá Omo Ekiti lemi amò ede ha jora yiyè.

      Delete
    2. Ha iyan a yun lerun re awe
      Nle kee
      Omo owa, omo ekun
      Emi omo ujesa lomi ki o

      Delete
  67. Awa na nkie o iya afin dimorkokorkus. Awon irumole na ki e pelu. Wagbo wato, wadagba, wadogbo. Omo gidi nie, sugbon wahala e ti poju nigbami. Odabo o.

    ReplyDelete
  68. You guys should slow down!! Allow us join in the fun now? Translate biko for us non yoruba speakers.....

    ReplyDelete
  69. Irumole nikan ko, sango ni...hehehehehehe


    Stella, how u go take know if people yab u 4 ds post now?abi u go moderate comments 4 ds post too?lol

    ReplyDelete
  70. Stella, kosi blog ti o dabi tire lailai!! Olorun a de ma fun ese. Akoba adaba ko ni je tie. Olorun a wa pelu iwo ati ebi re. Oore ofe Jesu ko ni tan ni ile ti ti lailai, Amin!!!

    ReplyDelete
  71. Stella boo ni?
    Se da da ni?
    Oko re ati omo re to fine yen kor?
    Bawo ni gbogbo germany?
    Njare se ole bami Waa oyinbo to ni buruku owo lowo...jo fii sokan. Kikikikikikikikikiki

    Eyin temi ni bi yi
    Se Eri wipe awon ta na (ede ana) lo poju lo ri bulogi yi
    Oga Oo
    Awon de lo seke ju..hahahha

    Sugbon stella se mi lopolopo
    Iru aworan woh lofi reprenti awon omo yoruba bayi
    Emi o nife si rara
    Eni na dabi irumole

    Oya na
    Leggooo

    ReplyDelete
  72. E ka san gbo gbo ile, se dada le wa.

    ReplyDelete
  73. E ka san gbo gbo ile, se dada le wa.

    ReplyDelete
  74. Ndi ofe mmanu, e kabo o
    se dada le wa
    eku ise, eku duro, eku ijoko, eku ojo o,
    se e ri oju,
    they can greet you die and they sebi curse;

    ReplyDelete
  75. Yorùbá eniyan idi ti ṣe ti o buruku korira igbos ki Elo. O ti wa ni bayi una Tan ki rii una ko si misyarnooo .

    ReplyDelete
  76. Stella...o ga gan ni, aworan ti o fi ki awon Yoruba yii o ni bo se je o......kikikiki
    E mi sha ma gbadun e nigba kigba.E ku igbadun.Eyin eyan mi....è jo e ba mi de bulogii mi o ki e ran mi lowo......www.onometalkam.com.
    Naijiria o ni baje o

    ReplyDelete
  77. Stella...o ga gan ni, aworan ti o fi ki awon Yoruba yii o ni bo se je o......kikikiki
    E mi sha ma gbadun e nigba kigba.E ku igbadun.Eyin eyan mi....è jo e ba mi de bulogii mi o ki e ran mi lowo......www.onometalkam.com.
    Naijiria o ni baje o

    ReplyDelete
  78. All my people how una dey. E mi Omo kwara. But I don't know how to speak the language. Eku blog oh.

    ReplyDelete
  79. Mo ki gbogbo omo karo o jire to wa ni blog yi.e je ki a ma fi ife ba ara wa lo o.inu mi dun gidi gan fun post yi, e dakun e ji ki a ma wu iwa bi Eni ti won ko ti otun gbo eko, ki iyato wa laarin awa ati awon omo aje okuta ma mu omi ti o je wipe wo jo ara won loju, awon ti won ma fi ipa ji iya won Lori bedi.oodua a gbe wa o

    ReplyDelete
  80. awon ajokuta ma moomi ti fe gan mona fun gbogbo yooba yi. irunmole nbe nigbale,won kio!

    ReplyDelete
  81. Okurin lowon be
    Obirin lowon be
    Gbo gbo eniyan lowon be
    Baye sent dalo ni
    Opo to gbabe olorun....join me

    ReplyDelete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141