Stella Dimoko Korkus.com: Iranti Ohun Malegbagbe

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Thursday, July 19, 2018

Iranti Ohun Malegbagbe

Ah emi ni SDK oh..Se e ni Iranti ohun_






MO ranti igba kekere,ti aman Lo ki awon obi to bi obi WA.

Baba baba MI je agbe ti won ni oko cocoa, obi ati orishishi ohun ogbin.Bi aba ti gbolude olojogbogboro, ni ati ma te oko leti.Oman dun gidi nitori omode egbe wa man po.

Baba ati mama ma nso itan ijapa ologbon ewe, ere osupa to badale. Awon ni won komi bi won shen ka bibeli ni ede yoruba,bi ase na oja,bibowo fun agba ati ibagbepo awon eyan,bi asen shey epo pupa ati garri ki won todi ologbe.

Kini ohun malegbagbe, ti ako abi iriri Lara awon ti won bi obi wa ati obi wa???...

Olori Orente

41 comments:

  1. Γ€mΓ­n Γ²hΓΊn dΓ‘?😎😎😎😎

    ReplyDelete
    Replies
    1. Lady bug, Stella koleka pelu amin ohun
      Eshey iya gbogbo

      Delete
    2. Ibukun how are you?

      Delete
    3. Iya gbogbo ni looto. kilokann ninu oro

      Delete
    4. Iya gbogbo,amin yin ko correct o.

      Delete
  2. iya mama mi nikan ni no ba laye ki won to ku lodun to koja. iya agba KO mi ni bi a se ma n wo ago ati iye owo ni Yoruba. mo ni ife iya GBA Gan....

    wild rose

    ReplyDelete
    Replies
    1. Kolorun forun ke won
      Loto awon lokomi ni ago wiwo

      Delete
  3. I also remember going to the village as a kid. The first time I can remember, I remember crying that I wanted to follow them to the farm

    They eventually allowed me to and it turned out to be a horrible decision.

    The mosquitoes that dealt with me that day can only be imagined, they were really terrible. I cried for them to take me back home, for where! That was my last time going to any farm.


    But the tales by moonlight. Kai! Those ones were lit. I remember Mama Love, wife of the richest man in our side of village.

    She would gather us at night in front of her house and tell us stories upon stories.

    That was where I learnt this song from.

    Mbosi anyi jere onu mbada
    Mbada chanchan
    A Pa yi ozu ozo
    Mbada chanchan
    ..........


    Pardon me abeg, my igbo is really terrible

    ReplyDelete
  4. Olori Orente ba wo ni?
    se dada ni?

    biko translate in brief so dat i go fit chuk mouth small

    ReplyDelete
  5. SDK and Olori orente is all I can understand. @Princess Tever

    ReplyDelete
  6. I'm lost here, Olori.

    O di igba miπŸ€—πŸ€—

    ReplyDelete
    Replies
    1. Don't be lost
      Childhood memories with grandparents

      Delete
  7. Nice work Olori, i wish my yoruba in written form can be half as good as yours. But i can read well in yoruba. Eku ise ooo

    ReplyDelete
  8. we buy dead,scrap or faulty inverter battery call me.08117903918/0814139511319 July 2018 at 13:55

    Kilode

    ReplyDelete
  9. Ki lo so? Ejoo, Mi o gbo nkoto nso. Jejely wakaring pass

    ReplyDelete
    Replies
    1. Waka on. Gbogbo eniyan ko logbodo mo nkan ti won ko

      Delete
  10. 😘😘😘😘😘😘😘@olori orente. πŸ‘πŸ‘

    ReplyDelete
    Replies
    1. Amanda sweetie😘😘😘😘😘

      Delete
  11. Haa,monife si Itan yi o, emi gbe Lodo iya iyami nigba ti mo kere,iru ni mama Agba mi Nta,moranti aworan Igba ti mo pe odun kan,mama so pe mo feran ati ma gbe abo losi ile alamala pelu naira kan lati ra amala.

    ReplyDelete
  12. Ki iya ati baba iya mi to di ologbe, a lo ki won ni ilu wa. Iya mama mi mu mi lo si oko iresi, mo ri bi won se n'gbin iresi, inu mi ma dun si!

    Mo te le aburo mama mi lo si ibi ti won gbi isu si, ibe ni mo ti mo wi pe igi ti won ti fi obe gbe enu re ko le wa sho sho ro ni won ma fi'n wu isu ti o ti gbo ni ile, won o ki n'lo obe lasan.

    Oti pe ti mo ti lo si ilu wa jare.

    ReplyDelete
  13. Ogba kekere mi,moo man loo ilu waa fun @least 1week ninu holude,odo iya iya mi nii moo man nlo,won si nii oko ila ati a won ewe obe Miran,emi ati awon omo egbe ile wa man lo sk odo loo shere.ijo meji ni mio le gbagbe lai-lai:awa omo kekere lo so odo as usual,emio o kin WO inu e wee tori eeru man bami,sugbon moo man joko si etie with my legs in the river,sha Dede nii owo kan fa ESE mi mejeeji pelu full force moo de yo sinu omi,mio le swim so moo muu omi bii ademu kan(lol)ki won to sare gbemi soke(I don't believe till date it was anyone of us there that dragged me cos no one was in that direction+DT was d last time I went there..lol
    Ijo kan iya iya mi saa ila si ori okuta(lower part of a big mountain)won wa jade lo,eminikan nii moo wa ni ile ni irole and we pack the ila by 5pm,moo ba da lo so ori okuta loo koo ila,I waa half way when I heard a shaky audible voice asking me to leave it,I heard it 3×s and I ran so hard I coudnt talk for few mins...lol,my grandma thought I was only scared but I know what I heard,igba ti moo pada sii city,moo so fun iya mi pe mio loo fun holude moo....kikiki!!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Hahahahaha
      Opamilerin ohπŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚

      Delete
  14. Stella mo mo wipe iwo feran oko gidigan, o maa ngbadun e daada, iyen oko ti o tobi gan o, kii se oko kekere

    ReplyDelete
  15. Eku ise opolo olori....

    Iya iya mi nikan ni mo mo nitori awon obi baba mi ti Ku Lati igba ti baba mi wa ni omo odun meewa bo ti le jewipe baba mi ni iya awon ni mo jo.
    Igba ti iya iya mi Ku ni igba a ko ko ti molo si ilu, ah! Mo gbadun ara mi gidan tori a ma n lo si odo, ibe ni mo ti ko ko je akara elepo.
    Aye gbawa lati seere kiri yato so ile ti a kin ribi lo.
    Sugbon ni siyin, ko si arugbo kankan fun wa mo.

    ReplyDelete
  16. Iya baba mi je agbe takuntakun, oloko obi, koko ati osan sugbon emi ni imele gan nipa ise oko. Nigba isinmi olojo gbogboro ni iya agba ma nko emi ati awon aburo mi losi oko, sugbon nigbati emi bati ri abi pade kokoro ijalo lona oko, ise ojo yen ti pari niyen fun mi. Emi ko feran ise oko rara oh.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Hahahahahhaaha
      Jkool ole niyin oh
      Chai, ijalo ati ikaka kodara rara

      Delete
  17. E ku ise takuntakun,Olori.

    Mo sunmo iya iya mi ki won to Ku(ki olorun ba mi fi orun ke won). Aimoye ohun rere ti mi o le gbagbe nipa mama. Okan ninu e ni Oriki idile iya mi ti won ko mi. Nigba ti iya iya mi pa ipo da,emi nikan ninu gbogbo omo-omo ni mo ki maami ni oriki idile won. Inu a won eniyan dun gannn.Mo si ni aworan ibi ti mo ti n ki oku Maami nile.

    Maama je eni ti o ko gbogbo eniyan mo ra. Ko tenbelu enikeni(ti mo fi oju mi ri) ri. Won ma n so fun mi wi pe "oore o gbe". Ki a maa se oore ni gbogbo igba. Mo ko eyi lara Maami. Ire o.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Eshey ogbeni olayinka
      Sisunmo awon agbalagba ma n laniloye πŸ‘πŸ‘

      Delete
    2. Omidan Olayinka ni o.
      Beeni,Olori.
      Ilaniloye gidi gan ni o.

      Delete
  18. momagbadun iya to bi iya mi o. Ti o ba di igba olude nla bayi iya mama mi a wa ko wa lo si ogbomoso, ti a ba de ibe a ma n tele won lo si okoibe ni mo ti ko bi won shey n je isu sisun ati biwon ma n shey yan garri tori iya agba ni oko ege. sugbon o dun mi nigba ti mama pa ipo da nitori ise oko yen ba oju mama je pupo ko to dipe won ku.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Heya, omo ilu ogbomoso ni iya mi na

      Delete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141