Stella Dimoko Korkus.com: ORIKI IBEJI....

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, December 20, 2017

ORIKI IBEJI....

Awon eyan mi...kilon sele?..emi ni Stella lon soro....
Ama rira inside the post..hahahahahhahahaha


ORIKI IBEJI {EJIRE}


Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.
Ẹdúnjobí,
Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi,
Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,
Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.
Tani o bi ibeji ko n'owo?
Emi ooooo


Dedicated to all the Ẹ̀jìrẹ́s
Aku ipalemo Odun oooo
Abawa laye,ayo lama fi shey ooo


Bv Olori orente

47 comments:

 1. Winiwini loju orogun, o so ile alakisa di onigba aso.....emi wa a se pupo e

  ReplyDelete
  Replies
  1. Ejire, Ara isokun
   Okan MO bere
   Eji lowole tomiwa
   Owole alakisa so alakisa donigba aso.


   Tayelolu igese oni gba oko.

   Delete
  2. Ejire, ara isokun
   Edunjobi, okan nba bi, meji lowole tomiwa.
   Ebekishii, bekeshe,
   O beee sile alakiisa, o soo alakiisaa di oni igba aso.
   Winiwini loju oroogun, ejiworo loju
   iya ee.
   Buu mi kin baa e rele, yin mi kin pada leyin ree.
   Obaa omo. Afinju omo to n gba ikunle iya. Won a tun gba idobale baba won. etc. Hmmmm....how I love you guys.

   Delete
 2. Olori Orente, Iya Ibeji. Mo ki yin Ma. Emi ni Rowland, Ema se iyonu, e wa ninu adura mi. Ema gbagbe pe Mo nife yin gan. Eyin ati Omo Iya mi Mummy Twins Bee 10 ati Sharon Aminu.
  Ninu odun tuntun yi, nkan ti e fe olorun Ma se fu n yin. 💝💝💝

  ReplyDelete
  Replies
  1. Alagba Rowland, Eku ipalemo odun

   Delete
  2. Awwwww Omo iyami Row Rowland
   Amin loruko jesu
   Emi Na nife re pupo
   Adura waa magba....amin😘😘😘😘😘😘😘😘

   Delete
 3. Okan nba bi,meji lo wo letomi,tin ba bejire,inu mi aaadun oooo,eni bami bi beji kodi de joo,tentere

  ReplyDelete
 4. Tiri gbosa fun gbogbo ibeji to n be ninu blogu yi...
  Sdk, tuale fun yin o...
  Gbogbo ololufemi tin be ni yi, eku igbaladun..

  ReplyDelete
 5. Sun re o baba mi. Okunrin takun takun..... Keep Resting in peace my humble,hardworking and loving Dad. A friend spelled for me tho

  ReplyDelete
 6. ko easy lati to ibeji.
  Sugbon ti won ba dagba tan, won a MA dayan lorun

  ReplyDelete
 7. Awon goons mi,ekwu igbadun,ekwu odun,adafu gbogbowa oo"asheee"hope I did not murder Yoruba Lang?

  ReplyDelete
 8. Okan nba bi
  Eji lo wole to mi wa

  ReplyDelete
 9. I just recited it to my 9 months identical twin girls, Rinsola and Rinsire thanks for choosing me as your Manama, I love you scarra, twin baby dust to all ttc

  ReplyDelete
  Replies
  1. Amin Jesu
   Mofi rinsola ati rinsire toro lowo eledumare

   Delete
 10. Olori Orente talo nsoro?
  Mi obo ooo.
  Kile WI?

  ReplyDelete
  Replies
  1. Hahahhahahha
   Chike ooooo😀😀😀😀😀😀

   Delete
 11. Hahahhahahha Stella oooo
  Ekasan gbogbo ile
  Aku ipalemo Odun oooo
  Nkan Ayo oni wan Nile wa ooo
  Olorun apese gbo ini wa oo
  Awa ta toro ibeji, olorun afunwa
  Amin.

  ReplyDelete
 12. Awon ejire ni iyanyi, e n'le fa! hehehehe

  ReplyDelete
 13. I just recited it to my precious twin in Ma belly. I am patiently waiting for nine months to behold my King and queen. Emi gangan ni iya ibeji to be.

  ReplyDelete
 14. ibeji wunmi ooooo
  ibeji ni oga mi (twinsfaja)
  Olorun funmi ni omo meji bi o
  amin

  bv olori orente...ibeji is your portion
  bv bee10, Sharon aminu & all GTC women.. Olorun ti sign si twins yin


  ReplyDelete
  Replies
  1. Amin ooo, Omo iyami
   Bosemari niyen😇😇😇😇😇

   Delete
 15. ejire ara isokun. oriki nla, emi naa fe bi ibeji o. aku imura odun. emi wa ase opolopo e o. amin.

  ReplyDelete
 16. Inu mi dun pupo pupo leni. Oluwa ema se oo.

  ReplyDelete
 17. Mo kin everybody nibibai. Lol..hope i tried? My Yoruba is next to nothing. I don't understand nada of what you wrote buh I guess you're hailing twins. Since I'm a twin I collect the hailings too...lol.
  God will do yours in a while just believe.

  ReplyDelete
 18. Olori Orente....Iya Ibeji.
  Oriki ta ma ka fun a won ibeji yin lodun to n bo niyi loruko Jesu.

  ReplyDelete
 19. Epo be ewa be o
  Epo be ewa be o
  Aya mi o Ja o ye
  Aye mi o Ja
  Lati bi ibeji
  Epo be ewa be o
  Singing.....

  ReplyDelete
 20. Thanks orente! Na twins i be. My head dey swell weneva i hear this oriki!

  ReplyDelete
 21. Ejire ara isokun. Ejire ni baba mi, emi na si fe bi ibeji nitori omo ogbomoso ni mi, ejire si po pupo nilu WA. Olori orente ese pupo

  ReplyDelete
  Replies
  1. Awww ibeji ni iyami naa
   Omo ogbomoso naa ni
   Adupe oo

   Delete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210329280