Awa ti de.awon daaaaaa!!!!..heheheheheheehehe Oruko mi ni SDK,mo fe se intro ni...LMAO
ALAYE NIPA IRU AWON OMO WONYII
1.Omo ti o mu ese waye ni _(ige)
2.Omo tio ni ika mefa ni __(olugbodi)
3.Omo ti a bi si oju ona ni _(abiona)
4.Omo ti a bi nigba ti baba re ko si nile ni ____(bidemi)
5.Omo ti irun ori re ta koko ni __(dada)
6.Omo ti o wa ninu apo nigba ti a bii ni _____(oke)
7.Omo ti o gbe ibi ko orun waye -(ojo/aina)
8.Omo meji ti a bi leeka naa ni _(taye ati kehinde)
9. Ta ni alaba? (Omo ti a bi le idowu)
10.Omo ti baba re kun i kete ti a bii tan ni ____(babarimisa)
11. Omo ti o kere pupo nigba ti a bii ni _____(kiyeseni)
12.Iru omo wo ni a n pe ni kasimaawoo?
--- Abiku omo.
Bawo ni a se n fi awon nnkan wonyii se adura nibi isomoloruko?
1.Aadun- ki aye omo naa ladun
2.Oyin- ki aye omo naa loyin
3. Ataare-ki aye maa soro re nire, ko sin i omo pupo bii ataare
4. Orogbo- ko dagba, ko dogbo
5.Obi- ki obi bi iku ati arun danu
6. Eja gbigbe- otutu kii meja lale odo, aye ko nii gbona moo
7. Eku gbigbe- ki eku maa ke bii eku, ki eye maa ke bii eye, ki aye re maa lo daadaa
8. Ireke- adun nit i ireke ki aye re ladun
9.Omi-ki aye mase ba omo tuntun naa se ota,nitori pe a kii ba omi sota.
10.Oti- aye omo tuntun naa ko gbodo ti
Sugbon laye ode oni, esin ti gba opolopo asa lowo wa. Bawo la shey nsomoloruko nidele wa????
Olori Orente
We are talking about naming ceremony and how important the olden days people cherish the use of honey,water,kolanut and bitter kola. But due to religion,most homes don't practice them anymore.
Eto Pataki lomo bibi, iya aburo ku ewu. Olori orente aya baba, a kan e layi pe layi jina ni oruko Jesus, amin
ReplyDeleteAmin loruko jesu
DeleteModupe eyan iyi
Amin.
DeleteEbun pataki lomo bibi. Not eto. Thank me later
DeleteBeautiful piece... so educating
ReplyDeleterubbish
DeleteYoruba people oya na una time be dis
ReplyDeleteThis one strong o
ReplyDeleteUna head set house, miss ess I sight you
ReplyDeleteOmo Ibadan ni.. .Omo ajegbin je ikaraun.. Omo ajorosun...
ReplyDeleteLori oro ti iyaafin Olori orente so...
Awon ebi kan sin se, especially(mi mo ni ede Yoruba) ebi Ti awon iya agba ati baba agba ti won feran asa ati Ise..
Omo Ibadan ni emi naa. Awon ti won omon Ibadan kii ni won maan kiwon ni Omo ajegbin jekarahun.
DeleteBayi ni Oriki Ibadan
Omo ajegbin yo, Omo ajoro sun, omo afikarahun forimu. Ibadan Ilu Ogunmola, Ilu Ajayi olodogbo Keri loju Ogun.
Olori Orente, eku ise opolo, Oodua aagbewa o
*Larry was here*
Eyin omo Ibadan mokiyin ooπππ
DeleteOmo Ibadan kiniso re?
DeleteAwon ijo alaso funfun si nlo gbo nkan wonyi lati fi somo loruko.
Olori ekuse oo.
Gooday beautiful people
ReplyDeleteThis Yoruba hard small for me today o, Abi I Don forget my skills again?
ReplyDeleteEku ise takun takun Olori..ayo akaari.
ReplyDeleteLooto ni esin ti GBA opolopo asa kuro lowo wa.
Gege bi esin temi, ti a ba bi omo okunrin a ma n pa agbo eran meji sugbon ti o ba he obinrin a ma pa eyokan ni ojo kejo ti a ba bimo botileje wipe a won eyan mi a ma somoloruko ni ojo keje ninu esin wa.
Ni ojo keje ni a ma fun omo ni oruko inu esin sugbon eyi koda oruko abiso duro gegebi e ti so isele to ba we lo ma sokunfa iru oruko na bi apeere ni oluwadurotimi ti omo ni nje nitori gbogbo ohun to sele ki n to ribi.
O digba kan na.
Beeni
DeleteEbami ki omomi ππ
Oluwa yi o si duro ti gbogbo wa ati awon omo wa dede. A jere gbogbo won ni oruko JESU π.
DeleteOlori Orente, e ku ise naa iya mi. Ooduwa a gbe yin
E gbiyanju bi e se ko gbogbo nka wonyi ni ede abinibi Yoruba.
DeleteAye ti di aye olaju sugbon awon idile kan si n tele awon ilana idile won lati so omo loruko paapa julo ni awon ilu oke. Awon Alfa ati Pasito lo n se ojuse wonyi julo ni igboro laye ode oni. Ki Olorun fi omo rere ke gbogbo eniyan ti o n woju Oluwa fun ire isomoloruko yi. Ire a kaari gbogbo wa lase Edumare.
ReplyDeleteOloori Orente, oya mark this my WAEC paper over 100%. I must show my MIL my score card o. Lol
Hahahahahhahaa
DeleteMama oh, owo kan funyin oo
100% gerege πππππ
Yaaay! 100%!! Thanks Oloori. Much love.
DeleteAmebonawork, me sef give you 100%. Twaaaaaale iya mi, mi ko mo wipe omo Oduuwa ni yin Iya ile okan πππ "Amebonawork" Mi o bu yin ooooo, mo translate oruko yin lati ede geesi si ede abi ni bi ni oooo ππππππ.
DeleteE ku ise taakun taakun Olori mi. ππΎππ
Ile l'an wo ki a to so Omo l'oruko
ReplyDeleteOmo iya, booni
DeleteAku ojo meta
I got f9 in Yoruba
ReplyDeleteNo matter how hard I tried
I Dont think I can know how to speak Yoruba fluently .
Vera shame on you.. Lol
Hahahahaha
DeleteYou can start learning now
I understand but I can't speak. I can't speak any language sef
DeleteLafresh I understand small edo
DeleteKada, ofure πππ
Beeni olaju lode toba aye je,moferan Igba atijo ju aiye ode oni, lagbara oloorun olori orente ti e Na pelu loruko Jesu, wafi owo osun Pa omo lara, ogede kigbe odo koya agan, omo were Nile eh lase edumare.
ReplyDeleteAminnnnnn iyami
DeleteEshey gan
Benni
DeleteSe aye isin yi si ma n'tele asa yi sha? Mi ko ro be.
ReplyDeleteAsa ode ti oni ni ki awon yoruba ma so omo ni oruko pupo.
Iya oko ma ni oruko ti won, baa kan naa ni fun baba oko, iya iyawo, baba iyawo ati be be lo. Oga oju!
Omo Iya mi, boo ni? Aa to kan wa ni Oruko nla ti jesu, amin....
Vera, wawo omo iyami ton so yoruba gidi
DeleteAmin eyan iyi, ire na akari wa
LOL I tried so hard to read some of the Yoruba. Thank you so much Olori Orente! This brought back lovely memories. I remember those days when naming ceremonies were conducted like this. Eku, Eja, Omi Adun and they will put these things in the baby's mouth also. I use to love to eat the left over as a child, especially Adun; Aye wa adun kale...Amin. Some families also have specific "oro" that they do eg: my family puts a knife in the baby's hand to make the baby a warrior.
ReplyDeleteπππππ
DeleteOlori Orente eku ise opolo,Olorun a first imo kun imo ni ase Edumare,Amin
ReplyDeleteMorning ki gbogbo omo kaaro ojire o
Eshey moma Ella
DeleteNoma Ella, this brought good memories. Na my late mum I remember now with the "omo karo ojire".
DeleteI had to start speaking Yoruba to my children when I saw a 7yr old boy speak Yoruba so much and I asked his mum if he goes to Nigeria on holiday and she said he's never been to Nigeria "say what"? π π.
I have tried in the past but now I have decided to try harder. My only disadvantage is my husband is Yoruba but understands but can't speak and my children's Minder na Oyinbo, So after school they are with her till I pick them up in the evening but na Yoruba I dey speak now for house with sign language to interpret it to them. God help me πππππ, its so funny but my children are loving it.
Anonymous 8:26
DeletePlease continue to speak to them, gradually they will understand.
Thanks my sister. Much love iya mi "Olori"
DeleteOlorun yoo bukun aye re! Amin! Amin! Amin ni oruko Jesu!
DeleteαΊΈlαΊΉwΓ αΉ£ugbα»n Mo fαΊΉ awα»n orin bi Omo la o fi gbe e e, Omo la o fi gbe.
ReplyDelete